Miss Grand International
Appearance
Miss Grand International Organisation | |
---|---|
มิสแกรนด์อินเตอร์เนชันแนล | |
Ifihan pupopupo | |
Agekuru | MGI |
Awọn ipilẹ | 23 Kọkànlá Oṣù 2013 |
Motto | (En) Stop the wars and violence |
Iṣakoso | |
Olori | Nawat Itsaragrisil |
Igbakeji piresidenti | Teresa Chaivisut |
Agbegbe | Ni kariaye |
Ile Olori Ise patapata | Bangkok, Tháílàndì |
Adirẹsi | 1213/414, Soi Lat Phrao 94 (Pancha Mit), Lat Phrao Road, Phapphla, Wang Thonglang, Bangkok, Tháílàndì |
Ọmọ ẹgbẹ | > Awọn orilẹ-ede 70 |
Miss Grand International | Valentina Figuera (2019) |
Agbari ti o ni ibatan | |
Nwe | Miss Grand International Co., Ltd. |
Sub-organisation | Miss Grand Thailand Co., Ltd. |
Media lori ayelujara | |
Oju opo wẹẹbu | MissGrandInternational.com |
Miss Grand International 2020 |
Miss Grand International jẹ idije ẹwa kariaye fun awọn obinrin alailẹgbẹ. Ti ipilẹṣẹ ni Tháílàndì ni ọdun 2013.[1][2]
Ni ọdun 2019, keje iru rẹ to waye nilu Caracas Fenesuela lọjọ 25, oṣu Kẹwa, Omidan Valentina Figuera, to jẹ́ aṣoju orilẹede Fenesuela lo jawe olubori nibi eto naa. Orilẹ-ede ọgọta lo kopa ninu idije naa.[3]
Winner
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdun | Miss Grand International | Orilẹ-ede | Ibi isere | Aṣoju obinrin |
---|---|---|---|---|
2013 | Janelee Chaparro[1] | Púẹ́rtò Ríkò | Nonthaburi, Tháílàndì | 71 |
2014 | Lees Garcia[4][5] | Kúbà | Bangkok, Tháílàndì | 85 |
2015 | Anea Garcia[6] | Orílẹ̀òmìnira Dómíníkì | Bangkok, Tháílàndì | 77 |
Claire Elizabeth Parker[6] | Austrálíà | |||
2016 | Ariska Putri Pertiwi[1][7] | Indonésíà | Las Vegas, Orílẹ̀ èdè America | 74 |
2017 | María José Lora[8] | Perú | Phú Quốc, Fiẹtnám | 77 |
2018 | Clara Sosa[9][10] | Paragúáì | Yangon, Myanmar | 75 |
2019 | Valentina Figuera[3] | Fenesuela | Caracas, Fenesuela | 60 |
2020 | Abena Appiah | Orílẹ̀ èdè America | Bangkok, Tháílàndì | 63 |
2021 | Nguyễn Thúc Thùy Tiên | Fiẹtnám | Bangkok, Tháílàndì | 59 |
2022 | Isabella Menin | Brasil | Jakarta, Indonésíà | 68 |
2023 | Luciana Fuster | Perú | Ho Chi Minh City, Fiẹtnám | 69 |
Fọto
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
Miss Grand International 2023
Luciana Fuster, Perú -
Miss Grand International 2022
Isabella Menin, Brasil -
Miss Grand International 2021
Nguyễn Thúc Thùy Tiên, Fiẹtnám -
Miss Grand International 2020
Abena Appiah, Orílẹ̀ èdè America -
Miss Grand International 2019
Valentina Figuera, Fenesuela -
Miss Grand International 2018
Clara Sosa, Paragúáì -
Miss Grand International 2017
María José Lora, Perú -
Miss Grand International 2016
Ariska Putri Pertiwi, Indonésíà -
Miss Grand International 2015
Claire Elizabeth Parker, Austrálíà -
Miss Grand International 2014
Lees Garcia, Kúbà -
Miss Grand International 2013
Janelee Chaparro, Púẹ́rtò Ríkò
Awọn aṣoju awọn orilẹ-ede ti o sọ Èdè Yorùbá
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tógò ati Benin ko darapọ mọ idije naa. Nàìjíríà bẹrẹ si kopa ninu idije naa lati ọdun 2014.
Bọtini awọ
- Winner
- Finalist
- Semifinalist
Miss Grand Nàìjíríà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdun | Miss Grand Nàìjíríà | Idije t’orilẹ-ede | Ọjọ ori | Height | Ilu | Placement | Ebun pataki |
---|---|---|---|---|---|---|---|
2013 | Marian Usinzibe Makbere | Appointed | Yenagoa | Ko darapọ mọ idije naa. | |||
2014 | Tessy Kiri Bibowei[11] | Miss Earth Nigeria 2013 | 25 | Abuja | — | — | |
2015 | Ifeoma Jennifer Ohia[12] | Miss Grand Nigeria 2015 | 22 | 183 cm | Lagos | — | — |
2016 | Rachel Onuwa Ikekhuame[13] | Miss Grand Nigeria 2016 | 25 | 174 cm | Lagos | — | — |
2017 | Princess Omowunmi Agunbiade | Miss Grand Nigeria 2017 | 21 | 174 cm | Abuja | — | — |
2018 | Ko si aṣoju | ||||||
2019 | Favour Oonye Ocheche | Appointed | 20 | 182 cm | Oturkpo | — |
|
Awon itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Voltaire E. Tayag (2017-10-21). "Miss Grand International: A Pageant for Peace". The Rappler (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-07-15. Retrieved 2019-11-11.
- ↑ Alexa Villano (2019-10-23). "What you need to know about the Miss Grand International pageant". The Rappler (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-10-24. Retrieved 2019-11-11.
- ↑ 3.0 3.1 Metro Puerto Rico (2019-10-28). "Valentina Figuera conquista Miss Grand International en su tierra" (in Èdè Pọtogí). Archived from the original on 2019-11-05. Retrieved 2019-10-30.
- ↑ Hot in Juba (2014). "Miss Grand International Lees Garcia is in Juba" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-09-27. Retrieved 2019-11-12.
- ↑ Miss Grand International (2015-05-23). "Lees Garcia - Miss Grand International 2014 Inside The Refugee Camp" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-11.
- ↑ 6.0 6.1 Jenna Clarke (2016-03-02). "Sexual assault allegations engulf Miss Grand International as Claire Parker adopts crown". The Sydney Morning Herald (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-11-11. Retrieved 2019-11-11.
- ↑ Concurso Nacionalde Beleza (2017-04-21). "Conheça os detalhes sobre o Miss Grand International 2017!" (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2018-04-27.
- ↑ Global Beauties (2017-10-25). "Miss Grand International 2017 is Miss Peru!" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-05-08. Retrieved 2018-04-27.
- ↑ Rappler.com (2018-10-26). "Miss Grand International 2018 Clara Sosa faints on stage after winning title" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-11-23. Retrieved 2018-11-12.
- ↑ Testbook.com (2018) (in en). Current Affairs Capsule October 2018. October 2018. Testbook.com. p. 28. https://books.google.co.th/books?id=JdqZDwAAQBAJ&pg=PA28&lpg=PA28&dq=Miss+Grand+International+Asia+America&source=bl&ots=fgthRK-HAX&sig=ACfU3U2wXTs1b7TR9mFWrQAjk0Hp6E0zPw&hl=th&sa=X&ved=2ahUKEwif36TflePlAhXbiHAKHXv1At84ChDoATAPegQICRAB#v=onepage&q=Miss%20Grand%20International%20Asia%20America&f=false.
- ↑ Miss Grand International (2014). "Miss Grand nigeria 2014" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2019-11-06. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ Oluwamitosin Tobun (2015-09-15). "Photos From The Miss Grand Nigeria 2015 Pageant" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). The Spark Nigeria. Archived from the original on 2020-06-09. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ Stella Dimoko Korkus (2016-09-26). "Rachael Onuwa Ikekhuame Wins Miss Grand Nigeria 2016" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Stelladimokokorkus.com. Retrieved 2020-06-09.
External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Official website of Miss Grand International
- Miss Grand International on Facebook
- Miss Grand International on Instagram
- Miss Grand International on Twitter
- Miss Grand International on Youtube
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Miss Grand International |