Mode 9
Ìrísí
Modenine | |
---|---|
Modenine performing on stage | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Babatunde Olusegun Adewale |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Nigel Benn, Samurai IX, Polimaf. |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kẹfà 1975 London, United Kingdom |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Osun State, Nigeria |
Irú orin | Rap, Hip hop |
Occupation(s) | Rapper, Lyricist |
Years active | 1999 to present |
Labels | Redeye Muzik |
Associated acts | Illbliss , Str8buttah, Swatroot, Tribes men, Ice Prince , Jesse Jags , Jonah the Monarch, Kraft, Alias, Black Intelligence, Cobhams Asuquo , 2 Face Idibia, Sticky ya Bongtur, Jeremiah Gyang , Chopstix , Mills the producer, Cashino NDT, Gold Lynx, Terry the Rapman , Overdose, B Elect, Shehu Adams, Mike Aremu . |
Website | officialmodenine.com |
Babatunde Olusegun Adewale[1][2](tí wọ́n bí ní June 14, 1975), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Modenine, jẹ́ olórin.[3][4] Ní ọdún 2014, ó ṣàgbéjáde orin kan, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Super Human" pẹ̀lú akọrin ti orílẹ̀-èdè Jamaica kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Canibus.[5][6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "MODE 9 goes emotional: I released an album, no one cared!". vanguardngr.com. Retrieved 26 September 2014.
- ↑ "Mode Nine". Pulse Nigeria. April 9, 2014.
- ↑ "MI is a better Rapper than Iceprince -- Mode 9". hiphopworldmagazine.com. Archived from the original on 2 February 2014. Retrieved 26 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Mode9 to quit rap music". punchng.com. Archived from the original on 24 September 2015. Retrieved 26 September 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Modenine & Canibus – Super Human (Prod. Teck-Zilla)". notjustok.com. Archived from the original on 24 August 2014. Retrieved 26 September 2014.
- ↑ "MODE 9 SIGNS NEW RECORD DEAL". March 22, 2012.