Modibo Adama

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Modibo Adama je ajagun Esin Islam, lati eya Fulani, o si je omo lehin, Usuman dan Fodiyo. Modibbo Adama ja jihad ni agbegbe Fombina ni ariwa orile ede Naijiria ati Kamerun, O si da Ijoba Fulani, sile, ni awon agbegbe wonii, eleyii, ti a mo si, Ijoba Fombina. Ijoba Fombina wa ni abe isakoso ijoba Kalifa Sokoto ni ariwa orile ede Naijiria. Modibbo Adama, fi olu-Ilu Ijoba ti o da sile, si ilu Yola, ni agbegbe Adámáwá, ni ariwa- Ila Orun Naijiria.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]