Moet Abebe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Moet Abebe
Ọjọ́ìbíLaura Monyeazo Abebe
29 Oṣù Keje 1989 (1989-07-29) (ọmọ ọdún 34)
United Kingdom, England
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Manchester
Law[1]
Iṣẹ́Video jockey [2], Radio Host, Òṣèrébìnrin[3], Catering Executive,
Ìgbà iṣẹ́2012–present

Laura Monyeazo Abebe (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógbọ̀n oṣù keje ọdún 1989) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Moet Abebe, jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré ni Nàìjíríà.[4] Ó béèrè sì ni di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tí ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni ṣíṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún Soundcity TV.[5] Ó ń má ṣe atọkun fún eto One on One show, Body & Soul ati Global Countdown Show . Ní gbà ti o wa ni Soundcity, ó kópa nínú àwọn ère bíi Red card, Oasis ati Living arrangements.[6] Ní ọdún 2016, ó bẹ́ẹ̀rẹ̀ sì ni ṣe atọkun fún eto" The Takeover" ni orí Soundcity Radio 95.8Fm.[7] Ó dá ilé iṣẹ́ ti won ti ta onje kale pẹlu ìyá rẹ, orúkọ ilé iṣẹ́ náà ni LM Occasions.[8]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọn bíi Laura sì orílẹ̀ èdè United Kingdom, ó sì lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Corona Ikoyi Primary School níbi tí ó tí ṣe ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Dowen College fún ọdún kan, kí ó tó wà lọ sí Woldingham School àti St. Teresa's Secondary school.[9] Ní ọdún 2008, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Manchester níbi tí ó tí kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ òfin.[10]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

TV & Radio Presenter[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó sì ṣe pẹlu Soundcity TV àti Soundcity radio.[11] Ó sì ti gbà àwọn gbajúmọ̀ olórin bíi Vector (rapper), 2Baba, Olamide, Chidinma àti D'banj lóri eto rẹ.[12]

Òṣeré[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó ti kó pá ninu awọn ère bíi Red card, Oasis àti Living Arrangement.[13]

Ẹ̀bùn[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Laura gba ẹ̀bùn Personality of the Month láti ọwọ Meets media[14], wọn si pèé fún ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ orí telefisionu tó tayọ julọ láti ọwọ Exquisite Magazine.[15]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Moet Abebe - Soundcity". Soundcity. July 17, 2021. Retrieved November 26, 2022. 
  2. "Moet Abebe condemns sex-for-date theory". Vanguard News. November 25, 2022. Retrieved November 26, 2022. 
  3. THISDAYLIVE, Home - (June 3, 2022). "Moët Abebe Signs New Deal with DSE Africa – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE. Archived from the original on November 26, 2022. Retrieved November 26, 2022. 
  4. JULIET EBIRIM (23 April 2015). "I believe in tasteful nudity – Moet Abebe". vanguardngr. Retrieved 14 May 2017. 
  5. "Moet Abebe On air Television Personality". Nigerianbiography. 13 September 2015. Retrieved 14 May 2017. 
  6. Taofik Bankole (23 March 2016). "Popular VJ, Moet Abebe shows off acting skills in new comedy series". Thenet. Retrieved 14 May 2017. 
  7. "Soundcity Radio 98.5". Soundcity. 31 July 2016. Retrieved 14 May 2017. 
  8. "Oap Moet Abebe Delves into Restaurant Business". Nathan Nathaniel Ekpo/Nollywoodgists.com. 25 January 2017. Retrieved 14 May 2017. 
  9. "Moet Abebe: Soundcity VJ goes back to village to bury grandfather". Ayomide O. Tayo. 29 October 2015. Retrieved 14 May 2017. 
  10. evatese.com Editor (16 June 2014). "All You Need To Know About Moet Abebe + Photos". evatese.com. Archived from the original on 26 April 2017. Retrieved 14 May 2017. 
  11. "SoundCity Presenter, Moet Abebe Apologizes To Fans Over Outburst". Owolabi Oluwasegun. Retrieved 13 May 2017. 
  12. "Vector The Viper ‘Dares’ Rappers on #TheTakeOver w/ Moet Abebe". Soundcity.tv. 5 February 2017. Retrieved 14 May 2017. 
  13. Sola (17 March 2017). "Moet Abebe and her engagement ring drama – we investigate (PHOTOS)". Ynaija. Retrieved 14 May 2017. 
  14. Geraldine Akutu (11 February 2017). "Meets Media celebrates Moet Abebe, Wizboy". guardian.ng. Retrieved 14 May 2017. 
  15. Ferdinand Ekechukwu (11 February 2017). "WizBoyy, Moet Abebe Emerge ‘Star Guests’". thisdaylive. Retrieved 14 May 2017.