Mohammed Bello El-Rufai
Ìrísí
Mohammed Bello El-Rufai | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria from Kaduna | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 11 June 2023 | |
Asíwájú | Samaila Suleiman |
Constituency | Kaduna North |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kínní 1988 Kaduna State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
Àwọn òbí |
|
Alma mater | |
Occupation |
|
Website | belloelrufai.com |
Mohammed Bello El-Rufai je oloselu omo orile-ede Naijiria, o n sise bayii gege bi omo ile igbimo asofin àgbá ni orile-ede Naijiria to n soju agbegbe Kaduna North Federal Constituency ni ile igbimo asofin agba 10th, [1] ati omo gomina ipinle Kaduna nígbà kan rii, Mallam Nasir El-Rufai. . O ti yan gẹgẹbi Igbimọ Ile Alaga lori Awọn Ilana Ile-ifowopamọ.