Moses Odunwa
Ìrísí
Moses Odunwa (ojoibi 1966) je oloselu omo orile-ede Naijiria ni ile igbimo asofin ipinle Ebonyi keje. Okan lara awon omo egbe oselu APC to n soju Ikwo South lo ti yan Nkemka Onuma ti won n soju ipinle Edda West State gẹ́gẹ́ bi agbẹnusọ ile igbimo asofin ìpínlè Ebonyi