Jump to content

Mount Zion Faith Ministries

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Mount Zion Faith Ministries jé isé iranse eré ìtàgé tí a ti owo Evang. Mike Bamiloye àti Gloria Bamiloye dálè ní odun 1985[1] Ète dídá isé iranse na kalè ni(gege bi Olùdásílè Mike Bamiloye sé so) láti se isé ihinrere kari aye àti láti sé igbero ìjo Olorun

Ní ojó kokanla, osù keje, odun 1986, isé iranse na se eré ìtàgé àkókó ní ilé ìwé St. Margaret girls granted school ní Ilesha, ní odún tó tele, Mike Bamiloye kowe fi isé sile láti gbojumo isé iranse Mount Zion Faith Ministries[2] Fiimu àkókò tí Mount Zion Faith Ministries se jáde ni "the inprofitable servant" ní odun 1990[3], léyìn ìgbàyí, wón tí sé olé ni igba(200) fiimu jáde. Òkan lára àwon fiimu won tó gbajugbaja ni "agbára nlá"

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "MZFM". About the Ministry. Archived from the original on October 12, 2022. Retrieved October 12, 2022. 
  2. ORISAKAHUNSI, Ifeoluwa (April 12, 2019). "MOUNT ZION FAITH MINISTRIES". gospelfilmsng. Archived from the original on October 12, 2022. Retrieved October 12, 2022. 
  3. "Complete List of Mount Zion Film Productions (1990-2019)". gospelfilmsng. April 12, 2019. Archived from the original on November 30, 2021. Retrieved October 12, 2022.