Jump to content

Mike Bamiloye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Mike Bámilóyè)

[1][2]

Michael Àbáyọ̀mí Bámilóyè (MAB)
Mike Bamiloye
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹrin 1960 (1960-04-13) (ọmọ ọdún 64)
Ìléṣà, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́
 • Evangelist
 • actor
 • filmmaker
 • producer
 • director
 • dramatist
Ìgbà iṣẹ́1985–present
Gbajúmọ̀ fúnChristian Drama
Olólùfẹ́Gloria Bámilóyè
Àwọn ọmọ
 • Joshua mike-Bámilóyè
 • Dámilọ́lá mike-Bámilóyè
 • Dárasími mike-Bámilóyè

Mike Ayọ̀bámi Bámilóyè ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [3] Ó jẹ́ ajíyìn-rere tí ó ma ń lo eré oníṣẹ́ láti fi jèrè ọkàn àwọn ènìyàn, ó sì tún jẹ́ Olùdásílẹ̀ àti Ààrẹ Mount Zion Faith Ministries[4] àti ti Mount Zion Television. Ó sì tú jẹ́ ọ̀kan lára ìjọ Christ Apostolic Church.

Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Mike ní ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960.[5] Ìyá rẹ̀ kú ní nígbà tí ó wà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin tí ó jẹ́ páítọ̀ Mrs. Felicia Adépọ̀jù Adésànyà ni ó tọ́jú rẹ̀ títí ó fi dàgbà kí ó tó lè mójú tó ara rẹ̀. Ó kẹ́kọ́ ní ilé-ékọ́

Divisional Teachers’ Training College ní ìlú Ìpetu-modù. Ó dá ìjọ Mount Zion ní ọjọ́ Karùún oṣù Kẹrin ọdún 1985. [6]

Eré tí ó gbé jáde ni Hell in Conference ni wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ ní National Christian Teachers Conference ní ọdún 1986 ní ìlú IléṣàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun .[7] Ó ti kópa, darí ati gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn. [8]

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní inú oṣù kẹ́jọ ọdún 1985, ìyàwó rẹ̀ arábìnrin Gloria Bámilóyè gbà láti jẹ́ aya rẹ̀, èyí ni ó sì bẹ̀rẹ̀ ìpìlẹ̀ ìjọ wọn (Mount Zion). Wọ́n bí àwọn ọmọ mẹ́rin (Damilola, Joshua, and Darasimi Mike-Bamiloye).[9]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Film Role Notes Ref(s)
Àpótí Ẹ̀rí'
1992 Agbára ńlá1-4 as Isawuru
2005 The Haunting Shadows 1
2005 The Haunting Shadows 2
2005 The Haunting Shadows 3 [10]
2006 The Forgotten Ones 1-4
2008 One Careless Night 1-5
The Ultimate Power 1-4
The Foundation
Broken Pitchers
Wounded Heart
Captive of the Mighty
Àṣìṣe Ńlá
The Gods Are Dead
Abejoye 1, 2 and 3
Shackles 1 & 2
2020 The Train (The journey of faith)

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
 1. ""Biography of Mike Bamiloye". (www.gospelfilmsng.com)". Archived from the original on 2020-08-12. Retrieved 2020-10-16. 
 2. ""Complete List of Mount Zion Movies". (www.gospelfilmsng.com)". Archived from the original on 2021-11-30. Retrieved 2020-10-16. 
 3. "Biography of Mike Bamiloye". Vanguard News. Archived from the original on 12 August 2020. Retrieved 25 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 4. "Biography of Mike Bamiloye". New Watch Times. Archived from the original on 12 August 2020. Retrieved 25 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 5. "Evangelist Mike Bamiloye warns Nigerians over fraudsters impersonating him". DailyPost Nigeria. Retrieved 25 February 2015. 
 6. "Dad is a great cook— Mike Bamiloye’s son". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 28 February 2015. Retrieved 25 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 7. "Adeboye urges Nollywood actors to seek supernatural help". Vanguard News. Retrieved 25 February 2015. 
 8. "How we moved from church drama to movies –Bamiloye". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 9. "I can't stop calling my husband brother mike-Gloria Bamiloye". Punchng.com. Retrieved 25 February 2015. 
 10. "The Haunting Shadows 3".  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Àdàkọ:Nigeria-bio-stub