Gloria Bámilóyè
Ìrísí
Gloria Bámilóyè | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Gloria Olúṣọlá Bámilóyè Ọjọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún 1964 Iléṣà, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1985 títí di àsìkò yìí |
Olólùfẹ́ | Mike Bámilóyè |
Gloria Olúṣọlá Bámilóyè tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹrin oṣù kejì ọdún 1964 jẹ́ gbajúmọ̀ olùdarí, Olóòtú Òṣerébìnri sinimá àgbéléwò, àti ònítíátà ọmọ bíbí ìlú Iléṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] She is a co-founder of Mount Zion Drama Ministry.[2]
Ìgbésí ayé rẹ̀ ni ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Gloria sí ìlú Iléṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́dún 1964. Ó kẹ́kọ̀ọ́ láti di olùkọ́ ní Divisional Teachers Training College ní ìlú Ìpetumọ̀dù.[3] Òun àti ọkọ rẹ̀, Mike Bámilóyè ni wọ́n jọ dá ilé iṣẹ́ sini á àgbéléwò Mount Zion Faith Ministry sílẹ̀ lọ́jọ́ karùn-ún oṣù kẹjọ ọdún 1985. Ó ti kópa, tí ó sìn ti darí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò àti eré orí ìtàgé lédè Yorùbá àti Gẹ̀ẹ́sì. [4] Lọ́dún 2002, ó kọ ìwé kan tí ó pe àkọlé rẹ̀ ní "The Anxiety of Single Sisters "[5]
Àtòjọ àṣàyàn àwọn sinimá rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Haunting Shadows 1 (2005)
- The Haunting Shadows 2 (2005)
- The Haunting Shadows 3 ( 2005)
- High calling 1, 2 & 3 (2020
- Strategies 1 & 2 (2020)
- My mother in law 1, 2 & 3 (2020)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Johnson-Odesola,-Mike-Bamiloye-and-Gloria-Bamiloye". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ TOPE OLUKOLE. "I didn’t reckon I’d marry Mike Bamiloye – Wife, Gloria". Newswatch Times. Archived from the original on 12 February 2016. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "I can’t stop calling my husband Brother Mike –Gloria Bamiloye". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ YEMISI ADENIRAN. "Poverty made us eat corn three times a day Gloria Bamiloye - nigeriafilms.com". nigeriafilms.com. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "The Anxiety of Single Sisters". google.co.za. Retrieved 25 February 2015.