Mike Bamiloye
Michael Àbáyọ̀mí Bámilóyè (MAB) | |
---|---|
Mike Bamiloye | |
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kẹrin 1960 Ìléṣà, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1985–present |
Gbajúmọ̀ fún | Christian Drama |
Olólùfẹ́ | Gloria Bámilóyè |
Àwọn ọmọ |
|
Mike Ayọ̀bámi Bámilóyè ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [3] Ó jẹ́ ajíyìn-rere tí ó ma ń lo eré oníṣẹ́ láti fi jèrè ọkàn àwọn ènìyàn, ó sì tún jẹ́ Olùdásílẹ̀ àti Ààrẹ Mount Zion Faith Ministries[4] àti ti Mount Zion Television. Ó sì tú jẹ́ ọ̀kan lára ìjọ Christ Apostolic Church.
Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Mike ní ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960.[5] Ìyá rẹ̀ kú ní nígbà tí ó wà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin tí ó jẹ́ páítọ̀ Mrs. Felicia Adépọ̀jù Adésànyà ni ó tọ́jú rẹ̀ títí ó fi dàgbà kí ó tó lè mójú tó ara rẹ̀. Ó kẹ́kọ́ ní ilé-ékọ́
Divisional Teachers’ Training College ní ìlú Ìpetu-modù. Ó dá ìjọ Mount Zion ní ọjọ́ Karùún oṣù Kẹrin ọdún 1985. [6]
Eré tí ó gbé jáde ni Hell in Conference ni wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ ní National Christian Teachers Conference ní ọdún 1986 ní ìlú Iléṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun .[7] Ó ti kópa, darí ati gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn. [8]
Ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní inú oṣù kẹ́jọ ọdún 1985, ìyàwó rẹ̀ arábìnrin Gloria Bámilóyè gbà láti jẹ́ aya rẹ̀, èyí ni ó sì bẹ̀rẹ̀ ìpìlẹ̀ ìjọ wọn (Mount Zion). Wọ́n bí àwọn ọmọ mẹ́rin (Damilola, Joshua, and Darasimi Mike-Bamiloye).[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Notes | Ref(s) |
---|---|---|---|---|
Àpótí Ẹ̀rí' | ||||
1992 | Agbára ńlá1-4 | as Isawuru | ||
2005 | The Haunting Shadows 1 | |||
2005 | The Haunting Shadows 2 | |||
2005 | The Haunting Shadows 3 | [10] | ||
2006 | The Forgotten Ones 1-4 | |||
2008 | One Careless Night 1-5 | |||
The Ultimate Power 1-4 | ||||
The Foundation | ||||
Broken Pitchers | ||||
Wounded Heart | ||||
Captive of the Mighty | ||||
Àṣìṣe Ńlá | ||||
The Gods Are Dead | ||||
Abejoye 1, 2 and 3 | ||||
Shackles 1 & 2 | ||||
2020 | The Train (The journey of faith) |
Ẹ tún lè wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ ""Biography of Mike Bamiloye". (www.gospelfilmsng.com)". Archived from the original on 2020-08-12. Retrieved 2020-10-16.
- ↑ ""Complete List of Mount Zion Movies". (www.gospelfilmsng.com)". Archived from the original on 2021-11-30. Retrieved 2020-10-16.
- ↑ "Biography of Mike Bamiloye". Vanguard News. Archived from the original on 12 August 2020. Retrieved 25 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Biography of Mike Bamiloye". New Watch Times. Archived from the original on 12 August 2020. Retrieved 25 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Evangelist Mike Bamiloye warns Nigerians over fraudsters impersonating him". DailyPost Nigeria. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "Dad is a great cook— Mike Bamiloye’s son". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 28 February 2015. Retrieved 25 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Adeboye urges Nollywood actors to seek supernatural help". Vanguard News. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "How we moved from church drama to movies –Bamiloye". Daily Independent, Nigerian Newspaper. Archived from the original on 25 February 2015. Retrieved 25 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "I can't stop calling my husband brother mike-Gloria Bamiloye". Punchng.com. Retrieved 25 February 2015.
- ↑ "The Haunting Shadows 3". Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)