Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adébọ̀wálé "Débọ̀" Adébáyọ̀ (tí a bí ní ọjọ́ kẹta, oṣù karùn-ún, ọdún 1993),[ 1] tí orúkọ ìnagijẹ́ rè jẹ́ Mr Macaroni , jẹ́ òṣèré orílè-èdè Nàìjíríà , apanilérìn-ín, afèròhàn-lórí-èrọ-ayéllujára àti ajà-fẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn.[ 2] [ 3] [ 4] Ó kọ́ bí a ṣe ń pani lérìn-ín, ó sì di gbajúmọ̀ látàrí àwọn fọ́nrán kékèèké rẹ̀ tó ti máa ń fi ara rẹ̀ hàn gẹ́gẹ́ bíi olóṣèlú kan tó lówó, tó sì fẹ́ máa fẹ́ àwọn ọ̀dómọbìnrin, nínú àwọn eré yìí, orúkọ rẹ̀ máa ń jẹ́ "Daddy Wa". Ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ Dẹ̀bọ̀ látàrí "Ooin", "Freaky freaky" àti "You are doing well" tó máa ń sọ ní gbogbo ìgbà nínú àwọn fọ́nrán rẹ̀.[ 5] [ 6]
Ọdún
Àkọ́lé
Ipa
Ọ̀rọ̀ ní ṣókí
Ìtọ́kasí
2021
Ponzi
Uchenna
Ponzi jẹ́ fíìmù apanilẹ́rì-ín tó jáde ní ọdún 2022, tó dá lórí jíja ènìyàn ní jìbìtì.
[ 7] [ 8]
Ayinla
Bayowa
Ayinla jẹ́ fíìmù olórin kan, tó fi ìgbésíayé olórin apala kan, Ayinla Yusuf, tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Ayinla Omowura hàn. Olórin yìí ni amúgbalẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ tí orúkọ rè ń jẹ́ Bayewu gún paa ní ọjọ́ kẹfà, oṣù karùn-ún, ọdún 1980 ní ìlú Abẹ́òkúta .
[ 9] [ 10]
2022
Survivors
Survivors jẹ́ ìtàn kan nípa àwọn òsìṣẹ́ mẹkáníìkì méjì tí wọ́n ń siṣẹ́ ní ẹ̀gbẹ́ títì, tí wọ́n ṣalábàápàdé ọ̀daràn David tó kọ́ wọ́n bí wọ́n tí ń jí ènìyàn gbé.
Aníkúlápó
Akanji
Aníkúlápó ṣàlàyé ìtàn Saro, arákùrin kan tó ń wá ọ̀nà àti jẹ àti mu kiri. Nínú ìrìn-àjò rẹ̀ ni ó ti pàdé ìyàwó ọba tó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní fẹ́. Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló ṣe ikú pa á, tí ẹyẹ kan tí a mọ̀ sí Àkàlà sì ra ẹ̀mí rẹ̀ padà.
[ 11]
Àkọ́lé
Ipa
Ìtókasí
Okirika
Alaga
[ 12]
Ile Alayo
Sweet Daddy
[ 13]
Flatmates
AK 47
[ 14]
The Johnsons
Casper
[ 15]
Ọdún
Àmì-ẹ̀yẹ̀
Ìsọ̀rí
Èsì
Reference
2018
Best of Nollywood Awards
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
[ 16]
2020
The Future Awards Africa
Gbàá
[ 17] [ 18]
City People Music Award
Gbàá
[ 19]
2021
Net Honours
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
[ 20]
2022
Africa Magic Viewers' Choice Awards
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
[ 21] [ 22]
2021
Gage Awards
Online Comedian of the Year
Won
[ 23]
↑ "Mr Macaroni, from Nigerian comedian to EndSARS activist" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/media-56067641 .
↑ "Adebowale Adedayo" . IMDb . Retrieved 2022-09-27 .
↑ "Mr Macaroni, others in marathon #EndSARSProtest in Lagos" . Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 October 2020. Retrieved 2 March 2021 .
↑ "Broda Shaggi, Mr. Macaroni others top the list of digital content creators" . Premium Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 29 January 2021. Retrieved 2 March 2021 .
↑ "MrMacaroni (@mrmacaroni1) • Instagram photos and videos" . www.instagram.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-09-27 .
↑ "MR MACARONI - YouTube" . www.youtube.com . Retrieved 2022-09-27 .
↑ "Kayode Kasum: People's experience with MMM inspired 'Ponzi' " . TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 March 2021. Retrieved 3 April 2021 .
↑ Tv, Bn (1 March 2021). "Meet the Star-Studded Cast of Kayode Kasum's Comedy Film "Ponzi" + Watch the Trailer" . BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 April 2021 .
↑ "Shades of a Tragic Hero" . THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 July 2021. Retrieved 14 July 2021 .
↑ "Tunde Kelani commences movie on late Apala legend, Ayinla Omowura" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 11 December 2020. Retrieved 14 July 2021 .
↑ "TRAILER: Kunle Remi, Sola Sobowale, Mr Macaroni star in ‘Anikulapo’" . TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-08-15. Retrieved 2022-10-02 .
↑ Online, Tribune (2021-09-23). "‘Okirika’ revamped as Nollywood stars, StarTimes collaborate on new comedy series" . Tribune Online . Retrieved 2022-07-28 .
↑ "Mr Macaroni, Broda Shaggi to star in “Ile Alayo” showing on StarTimes" . Vanguard News . 2021-07-13. Retrieved 2022-07-28 .
↑ "My Flatmates – Mr macaroni on this one as AK47" . Abidon TV . 2021-10-16. Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2022-07-28 .
↑ "Mr Macaroni debuts on The Johnsons on Africa Magic" . News Express Nigeria Website . 2021-05-16. Archived from the original on 2022-12-12. Retrieved 2022-07-28 .
↑ Augoye, Jayne (10 December 2018). "BON Awards 2018: Tope Oshin, Tana Adelana win big" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 9 October 2021 .
↑ "Drum rolls! 🥁 Introducing the Winners of The Future Awards Africa #TFAA2020" . BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 November 2020. Retrieved 2 March 2021 .
↑ "FULL LIST: Mr. Macaroni, Rema, Sam Adeyemi win big at TFAA 2020" . TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 November 2020. Retrieved 2 March 2021 .
↑ "Winners Emerge At 2020 City People Music Awards [Full List]" . City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 December 2020. Retrieved 2 March 2021 .
↑ "Net Honours – The Class of 2021" . Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 7 September 2021 .
↑ "2022 Africa Magic Awards Nominees don land- See who dey list" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-60818021 .
↑ "Stan Nze, Osas Ighodaro win big - Full list of all di winners from 2022 AMVCA" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-61452928 .
↑ "Mr Macaroni, Nengi, Erica, Aisha Yesufu, Airopay make Gage awards 2021 nomination" . The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-02-22. Archived from the original on 2022-10-22. Retrieved 2022-10-27 .