Muhammad Garba
Ìrísí
Comrade Muhammad Garba | |
---|---|
Commissioner Ministry of Information | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 2015 | |
Gómìnà | Abdullahi Umar Ganduje |
Press Secretary Office of the Deputy Governor | |
In office 1999–2003 | |
Gómìnà | Rabiu Kwankwaso |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kọkànlá 1964 Kano, |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
Education | BA, MA |
Alma mater | Bayero University Kano |
Occupation | Journalist politician |
Muhammad Garba jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn Nàìjíríà ,[1] àti òṣèlú láti ìpínlẹ̀ Kano tí ó jẹ́ Kọmísọ́nà fún ìkéde.[2] àti ẹgbẹ́ kọmití International Federation of Journalists. [3]
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Muhammad ní Ọjọ́ Kejìlẹ́lógún oṣù kọkànlá ọdún 1965 ní agbẹ̀gbẹ̀ Yakasi, Kano Principal tí of Ipinle Kano. Ó lọ sí ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ kofa Nassarawa àti Teachers college ní Sumaila níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ kí ó tó tẹ̀síwájú ní Yunifásítì Báyéró, Kano.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Umar, Salim (10 January 2020). "PROFILE: Muhammad Garba, the Kano State Government Imagemaker". Platinum Post News. Retrieved 19 March 2020.
- ↑ "Kano: Ganduje retains some former commissioners in 'new cabinet'". Daily Trust. 13 October 2019. Retrieved 19 March 2020.
- ↑ Triumphnews, The (15 November 2019). "Meet Kano's New Commissioners (I)". THE TRIUMPH. Retrieved 19 March 2020.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Malam Muhammad Garba". Kano. Kano state Official website. 13 June 2018. Archived from the original on 3 December 2020. Retrieved 19 March 2020.
- ↑ Ibrahim, Umar (2 March 2020). "The Journey of a Versatile Journalist to the Peak". Platinum Post News. Retrieved 19 March 2020.