Jump to content

Muso Kunda Museum of Women

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Muso Kunda Museum of Women
Muso Kunda Museum of Women, Bamako
Building
LocationKorofina Nord, Bamako, Mali
Coordinates12°40′04″N 7°57′10″W / 12.6678°N 7.9528°W / 12.6678; -7.9528Coordinates: 12°40′04″N 7°57′10″W / 12.6678°N 7.9528°W / 12.6678; -7.9528

Muso Kunda Women's Museum, tí wọ́n dá kalẹ̀ ní ọdún 1995, jẹ́ musíọ́mù tí wọ́n dá kalẹ̀ láti ṣe ìgbé lárugẹ àwọn obìnrin ní orílẹ̀ èdè Mali. Ajà fẹ́tọ̀ọ́ obìnrin àti òpìtàn Adame Ba Konaré ni ó da kalẹ̀[1]Bomako. Ète musíọ́mù náà ni láti mú ìdúró bá fífi ojú kó obìnrin kéré, láti ṣe ìdánimọ̀ àwọn ohun ribiribi tí àwọn obìnrin ti ṣe láwùjọ, àti láti jà fẹ́tọ̀ọ́ àwọn obìnrin.

Adame ló dá musíọ́mù náà kalẹ̀ ní ọdún 1995[2] Adame ni ìyàwó ààrẹ Alpha Oumar Konaré.[1]

Ó dá musíọ́mù náà kalẹ̀ láti jà fẹ́tọ̀ọ́ obìnrin, àti láti jà fẹ́tọ̀ọ́ wọn. Ara ète fún ìdásílẹ̀ rẹ̀ ni láti ṣe ìgbé lárugẹ íṣẹ́ owó àwọn obìnrin ní ayé àtijọ́ àti ayé òde òní.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Maliweb (2021-03-23). "Mali: Muso Kunda, un musée de la femme unique en son genre à Bamako" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-03-23. Retrieved 2021-03-23. 
  2. Maxwell, Heather Anne (2002) (in en). Destiny's Divas: Wassolu Singing, Music Ideologies, and the Politics of Performance in Bamako, Mali. Indiana University. pp. 379. https://books.google.com/books?id=w0keAQAAMAAJ&q=Muso+Kunda. 
  3. "Objectifs du Musée de la Femme". musokunda.org (in Èdè Faransé). 2021-03-23. Archived from the original on 2021-03-23. Retrieved 2021-03-23.