Nínà Àtẹ̀lẹsẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nínà àtẹ̀lẹsẹ̀

Nínà Àtẹ̀lẹsẹ̀ tàbí bastinado jẹ́ ọ̀nà láti fa ìrora tàbí yẹ̀yẹ́ nípa nína àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ ẹlòmíràn, pàápàá jù lọ, ẹrú. Yàtò sí àwọn ọ̀nà míràn láti na ènìyàn, nínà àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ ma ń sábà fa ìrora ṣùgbọ́n kìí sábà ṣe ẹni tí wọ́n ń nà léṣe, wọ́n ma ń sábà lo ẹgba tínrín bi pankẹ́rẹ́.[1]

Àkọsílẹ̀ nípa nína àtẹ̀lẹ̀sẹ̀ tàbí bastinado ní Europe ní ọdún 1537, àti ní China ní ọdún 960.[2] Àwọn míràn gbàgbọ́ gbé Bíbélì tọ́kaṣí bastinado nínú Bíbélì Mímọ́ (Prov. 22:15; Lev. 19:20; Deut. 22:18), èyí sì fi hàn pé wọ́n ti ń lo ọ̀nà ìbáwí yìí láti ìṣẹ̀ṣẹ̀.[3]

Wọ́n lo ọ̀nà ìbáwí ní àwọn ilé ìwé Jẹ́mánì àti Austria ní àwọn ọdún 1950s.[4][5][6][7]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Flogging | punishment". 
  2. Rejali 2009, p. 274.
  3. "Bastinado". www.biblegateway.com. Retrieved 6 March 2014. 
  4. "Wimmersdorf: 270 Schläge auf die Fußsohlen" (in Èdè Jámánì). kurier.at. 15 October 2013. Retrieved 3 March 2014. 
  5. "krone.at" vom 29. März 2012 Berichte über Folter im Kinderheim auf der Hohen Warte; 3 March 2014
  6. Rejali 2009, p. 275.
  7. Ruxandra Cesereanu: An Overview of Political Torture in the Twentieth Century. p. 124f.