Nadia Lalami Laaroussi (ti a bi ni ọjọ kejidinlọgbọn osu kẹrin ọdun 1990 ni Casablanca ) jẹ olugbaa tẹnisi fun orilẹ-ede Morocco tẹlẹ.
Ninu iṣẹ rẹ, o bori awọn akọle ida'se meji ati akọle ajose meji lori Circuit Obirin ITF . Ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2011, ó dé ipò ada'se tó dára jù lọ ní àgbáyé ni ipò 322. Ni kọkàndínlógbon Oṣu Kẹjọ 2011, o dè ipo. 427 ni ipo ajose.
Ti nṣere fun Ilu Morocco ni Cup Fed, Lalami ni igbasilẹ iṣẹgun–ipadanu ti 18–12.
Ni 2011 Grand Prix SAR La Princesse Lalla Meryem ni Fes, o fi oju irugbin akọkọ ati oni ipo No.24, Aravane Rezaï rii ni ipele keji, o si di Omo orilẹ-ede Morocco elere idaraya lati de ipele keji ti o kangun si asekagba ti figagbaga WTA.