Nana Asmaʼu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nana AsmaÀdàkọ:Hamzau (Nana Uwar daje)
Ọjọ́ìbí1793
Sokoto Caliphate
Aláìsí1864 (ọmọ ọdún 70–71)
Sokoto Caliphate
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Orúkọ mírànNana Uwar daje Nana AsmaÀdàkọ:Hamzau bint Shehu Usman dan Fodiyo
Iṣẹ́Islamic scholar, Humanitarian Services, entrepreneur

Nana Asmaʾu Ha-Nana Asmaʾu.ogg pronunciation (gbogbo orúkọ rẹ̀ ni: Asmaʾu bint Shehu Usman dan Fodiyo, Lárúbáwá: نانا أسماء بنت عثمان فودي‎; 1793–1864) jẹ́ ọmọ ọba Fula, Akéwì, olùkọ́, àti ọmọ ọ̀lùdásílẹ̀ Sokoto Caliphate, Usman dan Fodio.[1] Ó jẹ́ ẹni tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yẹ́ sí ní apá àríwá Nàìjíríà. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ má ń fi ṣe àpèjúwe bí obìnrin ṣe le jẹ́ akọ̀wé tí yó sì wà láàyè ara rẹ̀ ni Islam, àwọn míràn tún ròó pé ó wà lára àwọn tó kọ́kọ́ bẹ̀rẹ̀ jíjà fún ètọ́ ọmọbìnrin ní ilẹ̀ Áfríkà.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nana Asma'u". rlp.hds.harvard.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-03-23. Retrieved 2020-05-26.