National Temple
Tẹmpili Orilẹ-ede jẹ aye ijọsin fún fún ijo Aposteli Nigeria ti o wa ni Olorunda-Ketu, Ipinle Eko . Aye ijosin náà le gbà tó ènìyàn 100,000.
Itan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 1969, Apejọ Ọdọọdun fún àwon Lagos, Western ati Northern Area (LAWNA) eyiti o maa n waye ni Ebute Metta ni a se ní Orishigun, ilu kan ni Ketu nitori pé àwon ti óún wá fún apejo naa un pọ si. Ni ọdun 1970, a se Apejọ náà ni Olorunda-Ketu.[1]
Ni 1979, Alaga agbegbe LAWNA kinni, Oloogbe Olusoagutan SG Adegboyega fi ipilẹ ilé ti a wa mo si National Temple lelẹ. Ni ọdun 1994, Oloogbe Olusoagutan Samuel Jemigbon se ilọsiwaju kikọ ilè naa ni akoko rẹ gẹgẹ bi Alaga agbegbe LAWNA kẹta. [2]
A pari kíkó National Temple ní 19 November 2011 lábé idari Olusoagutan Gabriel Olutola eni tí o so pé "ilé náà jé ilé tí a fi adura kó"[3] and "o si jé iranleti isokan ìjo." Ilé náà le gbà tó eniyan ogorun egbèrún(100,000)[4]
Àwon ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Temple". tac-lawna.org. January 6, 2013. Archived from the original on January 6, 2013. Retrieved September 12, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Empty citation (help)"National Temple Overview". Archived from the original on 6 January 2013. Retrieved 12 July 2015.
- ↑ Udodiong, Inemesit (August 14, 2017). "11 things that are never going to change about this denomination". Pulse Nigeria. Retrieved September 12, 2022.
- ↑ Nation, The (August 3, 2018). "We're repositioning at 100, says Apostolic Church The Nation Newspaper". The Nation Newspaper. Retrieved September 12, 2022.