News Agency of Nigeria
Ìrísí
Type | Federal State Unitary Enterprise |
---|---|
Founded | 10 Oṣù Kàrún 1976 |
Headquarters | Abuja, Nigeria |
Area served | Worldwide |
Key people | Buki Ponle |
Industry | State news agency |
Products | News media |
Owner(s) | Wholly owned by federal government (as federal unitary enterprise) |
Website | nannews.ng |
News Agency of Nigeria (NAN) jẹ́ ilé-iṣẹ́ agbódegbà ìròyìn tí ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè [[Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà|Nigeria] Federal Government of Nigeria gẹ́gẹ́ bí i ilé-iṣẹ́ amóhùnmáwòrán Nigerian Television Authority.[1] Wọ́n dá NAN sílẹ̀ láti ṣe àpínká ìròyìn káàkiri Nigeria àti àti fún àwọn àjọ ilẹ̀-òkèèrè, bákan láti ṣe àtakò àwọn ìròyìn òfegè tàbí ìròyìn irọ́ nípa Nigeria. [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ NAN. "About Us - News Agency of Nigeria Archived 27 January 2020 at the Wayback Machine.." NAN. 28 September 2012. Retrieved 29 September 2012.
- ↑ Babatunde 2004, p. 22.