Niara Bely

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Niara Bely (c.1790-1879) ti a mọ ni gbajumọ gẹgẹbi Elizabeth Bailey Gomez jẹ olori ti Luso-Ilẹ Afrika jẹ óniṣowo pataki ni Century ti okan dinlogum. Arabinrin na jafafa lori owo oko ẹru ṣiṣe ni Farenya, Ilẹ Guinea[1].

Itan Igbesi Àye Niara[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Niara Bely jẹ ọmọbinrin Emmanuel Gomez, Oludari ti Bakia ti Luso-Ilẹ Afrika ni ilẹ Guinea. Niara kawe ni Liverpool[2][3].

Ni ọdun 1809, Niara fẹ oniṣowo ẹru Stiles Edward Lightbourn[4] nibi ti wọn kọkọ gbe ni Bangalan. Bely ṣiṣe owo ni Farenya, Guinea. O bẹrẹ́ sini gbe ni ile alaja meji eyi to maa n pe nk Afin. Agbegbe yi di Abule nigbati Bely bẹrẹ iṣẹ owo oko ẹru, eleyi pada di ọna owo ṣiṣe lati oke ti Fouta Djallon.

Ni Ọjọ mẹta dinlogun, Óṣu January, ọdun 1852, ijọba ilẹ British ati Sierra Leone pẹlu apapọ oludari abule fagile owo oko ẹru ṣiṣe ni agbegbe naa. Mary Faber (Óniṣowo Ẹru) ri ayipada yi gẹẹbi ipalara fun owo rẹ parapọ pẹlu Niara Bely ati Charles lati lodi si ifagile naa ni odo to wa ni isalẹ ti Susu. Ija yi ni kogbe Faber, Bely ati Wilkinson ni ọdun 1855. Akoko yi ni owo oko ẹru ṣiṣe di afisẹyin eleyi lo mu ki awọn olowo oko ẹru bẹrẹ owo miran[5].

Iku Niara[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni ọjọ mẹfa dinlogun, óṣu April, ọdun 1879, Niara Bẹly ku eyi to jẹ ti ojiji lẹyin ti wọn si mimọ ni ijọ Anglican gẹgẹbi ọrọ ọkan lara awọn olubagbe rẹ. Ni akọkọ, A sin Niara si abẹ igi cheese ni arin abule ṣugbọn ni ọdun 1966, wọn gbẹ sare si agbegbe naa ti wọn sin oku rẹ si[6]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Slave Trade Expedition to Africa". Columbia Star - Columbia's locally owned weekly newspaper since 1963. 2006-06-16. Retrieved 2023-08-25. 
  2. Sparks, R.J. (2016). Africans in the Old South: Mapping Exceptional Lives across the Atlantic World. Harvard University Press. p. 79. ISBN 978-0-674-49516-6. https://books.google.com.ng/books?id=8ZC-CwAAQBAJ&pg=PA79. Retrieved 2023-08-25. 
  3. "Sirra Leone Live Music". Sirra Leone Live Music. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  4. "Elizabeth Frazer Skelton Facts for Kids". Kids encyclopedia facts. 2023-07-26. Retrieved 2023-08-25. 
  5. "1843 entire to 'Sir John Marshall CB, HMS Iris, COGH' redirected to Mauritius". Warcovers. Archived from the original on 2023-08-25. Retrieved 2023-08-25. 
  6. Columbia Star - Columbia's locally owned weekly newspaper since 1963 2004.