Nicanor Duarte

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nicanor Duarte

Nicanor Duarte Oscar Nicanor Duarte Frutos (a bí ni ọjọ́ kọkànlá oṣù Òwàrà, ọdun 1956) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀èdè Paraguayan tí ó jẹ àárẹ ní ọdún 2003 sí 2008. Ní 2013, Ààrẹ Horacio Cartes yan Duarte gẹ́gẹ́ bíi Aṣojú sí Argentina, ó joyè atọ́kùn ìbáṣepọ̀ dánmọ́rán ìlú sí ìlú láti ọdún 2013 sí 2016. Báyìí Duarte jẹ́ òye aṣojú -ṣofin tí kò ní gbèdéke.

Orúkọ rẹ̀ ìyàwó ni Maria Gloria.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]