Jump to content

Nkechi Blessing Sunday

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nkechi Blessing Sunday
Ọjọ́ìbíNkechi Blessing Sunday
14 Oṣù Kejì 1989 (1989-02-14) (ọmọ ọdún 35)
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Olu Abiodun Nursery and Primary school
Barachel Model College
Iléẹ̀kọ́ gígaLagos State University
Houdegbe North American University
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́2008
Gbajúmọ̀ fúnKafila omo ibadan (2012)
omoege lekki (2015)
The Ghost and the Tout (2018)
Fate of Alakada (2020)
Notable workNBS Foundation
Nkechi films production
Olólùfẹ́Single
Àwọn ọmọ1
Parent(s)
  • Gloria Obasi Sunday (mother)

Nkechi Blessing Sunday (a bíi ni ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kejì ọdún 1989) /{{{1}}}/[1] jẹ́ olùgbé ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Òṣèré orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Olóòtú fíìmù, adarí fíìmù àti screenwriter, wọ́n tọ dàgbà ní Surulere, ní ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ṣàgbéjáde fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀, Omoege Lekki[2] ní ọdún 2015, tí òun tìkalára rẹ̀ jẹ́ akópa, pẹ̀lú Yinka Quadri. Ní ọdùn 2016, Omoege Lekki gba àwọ́ọ̀dù MAYA wọ́n sì yan-an fun Revelation of the Year nínú Best of Nollywood Awards.

Ó tún ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí adarí àti alákoso àgbà ní ilé tí ń ṣe àwọn fíìmù ti Nkechi, àti NBS Foundation.[3]

Ìgbé-ayé ní Ìbẹ̀rẹ̀-pẹ̀pẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nkechi Blessing Sunday jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Abia,[4] ìpínlẹ̀ kan ní apa ibìkan ní gúsù-àríwá ti orílẹ̀-èdè Naijiria. Ó ka ẹ̀kọ́ àkọ́ bẹ̀rẹ̀ rẹ ní ilé-ẹ̀kọ́ ní Olu Abiodun, ní ìpínlẹ̀ Èkó àti ẹ̀kọ́ gíga ní Barachel Model College, ní ìpínlẹ̀ Èkó.[5] Ó kọ́ ẹ̀kọ́ olóṣù mẹ́fà ti diploma lórí ìmọ̀ theatre arts ní Fásitì ti ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì kọ́ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ International Relations ní Fásitì Houdegbe North American.[6]

Ní ọdún 2008, lẹ́yìn tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde láti Fásitì ti ìpínlẹ̀ Èkó, ọ̀rẹ́ rẹ̀ "Kemi Korede" ṣàwárí ìfẹ́ Nkechi sí eré ṣíṣe ó sì lò ó gẹ́gẹ́ bí akópa nínú eré-àgbéléwò rẹ̀ "Omo Bewaji".[6] Omo Bewaji jẹ́ àlùyọ ráḿpẹ́ fún-un nínú iṣẹ́-àyànṣe rẹ̀ tí ó sì mu mọ Emeka Duru, tí ó rànlọ́wọ́ láti kópa nínú Emem Isong movie; la iná àti òṣùṣù ọdún 2009.[6]

Ó di ìlú mọ̀ọ̀ká ní ọdún 2012, pẹ̀lú ipò olú-ẹ̀dá-ìtàn nínú Kafila Omo Ibadan, lẹ́yìn ìpàdé rẹ̀ pẹ̀lú olóótú náà, Temitope Bali ní ìlú South Africa, tí ó fún-un ní ipò olú-ẹ̀dá ìtàn nínú Kafila Omo Ibadan.[6] Ní ọjọ́ kínní oṣù kejì ọdún 2017, The Nigeria Carnival USA, ṣàfihàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára àwọn aṣojú wọn nínú abala kejì ti ayẹyẹ ọlọ́dọọdún orin, àṣà àti ẹ̀fẹ̀ Nàìjíríà ní orílẹ̀-èdèAmerika.[7] Ní ọdún 2018, ó kó ipa ẹ̀dá ìtàn tí wọ́n pè ní "Dora" nínú fíìmù The Ghost and the Tout, ní́èyí tí ó bí àwọ́ọ̀dù fún ní ọdún 2018 City People Movie Award fún àwọn òṣèré'bìnrin tó kátò jùlọ lọ́dún.[8] Ní ọdún 2020, Nkechi Blessing darí ètò[9] African Entertainment Awards USA ti ọdún 2018 papọ̀ pẹ̀lú Seun Sean Jimoh. Ní ọdún yẹn náà, ó wà lára àwọn òṣèré inú Fate of Alakada[10] gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá ìtàn tí ń ṣe Bisi. Ó jẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn nínú Tanwa Savage, The Cleanser, Omo Emi, àti Ise Ori, àti ipò amúgbálẹ̀gbẹ́ olú-ẹ̀dá ìtàn nínú Breaded Life, àti Olori Amolegbe.

Divorce rate is so high because people are ready for weddings, not marriage… Ya all waiting for me to post my wedding pictures before you believe I am married…LMAO! I NBS wants marriage and not a wedding ain’t ready to make my relationship your entertainment

-Nkechi Blessing[11]

Ní̀ ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹfà, ọdún 2021, Nkechi Blessing, sojú abeńkòó nípa ìgbéyàwó òun àti òṣèlú ìpínlẹ̀ Ekiti náà, Falegan Opeyemi David, lẹ́yìn tí ó fọ́n àwọn àwòrán ìgbéyàwó wọn sórí ìkànni Instagram ní ọjọ́-ìbí ẹ̀.[11] Ní ọjọ́ Ketàlélógún oṣù kẹsàn-án ọdún 2021, ó pàdánù ìyá rẹ "Gloria Obasi Sunday", nígbà tí ó ń gbaradì fún ìfilọ́lè àwọn eré-àgbéléwò rẹ̀ tí ó ṣeyebíye ní theatre Èkó tí ó tóbi jùlọ.[12]

Ní ọjọ́ kefà oṣù kérin, ọdún 2022, Nkechi Blessing fi léde lórí ìkànnì Instagram rẹ̀ pé òun ti fòpin sí ìgbéyàwó òun tí ó pé oṣù mẹ́wàá pẹ̀lú Falegan Opeyemi David. [13]

Àwọn fíìmù látọwọ́ Nkechi Blessing Sunday.

Year Film Role Notes
2008 Omo Bewaji Eré-oníṣe
2009 Through The Fire & Entanglement Eré-oníṣe
2012 Kafila Omo Ibadan Eré-oníṣe
2015 Omoege Lekki Eré-oníṣe
2017 Alakada Reloaded Fíìmù-ẹlẹ́fẹ̀
Yanga Niniola Eré-oníṣe
Asiko-Time Nkechi Eré-oníṣe
2018 The Ghost and the Tout Dora Ghost
Judasi Ojooluwa Eré-oníṣe
Unsane Esther Eré-oníṣe
Anniversary Bose Eré-oníṣe
Olori Amolegbe Iyalode Ladies Eré-oníṣe
Soulmate Azeezat Eré-oníṣe
Jadesola Mofe Eré-oníṣe
Fatherhood Eré-oníṣe
Aye Sokunkun Eré-oníṣe
Imoran Advice Eré-oníṣe
Aje Eré-oníṣe
Ebiti Eré-oníṣe
Broken Soul Tunrayo Eré-oníṣe
Orogun Aladie Chioma Eré-oníṣe
Lekki Guyz Joy Eré-oníṣe
Alagbawi 1 & 2 Detective Ola Eré-oníṣe
Aje Himan Eré-oníṣe
Ile Wa Eré-oníṣe
Duro Nurse Tope Eré-oníṣe
Dokita Miracle Cynthia Eré-oníṣe
Alaamu Judith Eré-oníṣe
2019 Ise Ori Eré-oníṣe
Akwa Ndu Ihuoma Eré-oníṣe
Wound Rosemary Eré-oníṣe
Plastic Girls Bolu Eré-oníṣe
Agidi Okan Tunmise Eré-oníṣe
Olopa Olorun Joke Eré-oníṣe
Babeje Fadekemi Eré-oníṣe
Broken Crown Sayo Eré-oníṣe
Hostel Babes Eré-oníṣe
Akanda Derayo Eré-oníṣe
Omo Emi Eré-oníṣe
2020 Fate of Alakada Bisi Action Comedy
2021 Tanwa Savage Comedy-Drama
The Cleanser Thriller
Breaded Life Dramedy
Amerah Eré-oníṣe
Year Film Role
2015 Omoege Lekki Olóòtú
2018 Judasi Olóòtú
Unsane Olóòtú
2021 Amerah[14] Olóòtú

Awards and nominations

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Event Prize Recipient Result
2016 Best of Nollywood Awards Revelation of the Year (female) Herself Wọ́n pèé
2018 City People Movie Award Fastest Rising Actress of the Year (Female) Wọ́n pèé
Most Promising Actress of the Year (Yoruba) Wọ́n pèé
Best Actress of the Year (Yoruba) Wọ́n pèé
Most Promising Actress of the Year (Yoruba) Gbàá
2019 Best Supporting Actress of the Year (Yoruba) Wọ́n pèé
2020 Best of Nollywood Awards Best Actress in a Lead role –Yoruba Wọ́n pèé

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Adigun, Sunday (18 February 2019). "How NKECHI BLESSING Celebrated Her 30th Birthday". City People Magazine. Retrieved 8 May 2021. 
  2. "Why I gave Yinka Quadri a lap dance in Omoge Lekki — Nkechi Blessing". Vanguard News. 18 September 2015. Retrieved 7 May 2021. 
  3. "Star Actress, NKECHI BLESSING, Holds 3-In-1 Party". City People Magazine. 31 August 2019. Retrieved 8 May 2021. 
  4. Ukwuoma, Newton-Ray (9 February 2019). "With N500m, You Can Tame Me —Actress, Nkechi Blessing Sunday". tribuneonlineng.com. Retrieved 8 May 2021. 
  5. "Nkechi Blessing Sunday Biograph". FabWoman Magazine. 14 February 2020. Retrieved 8 May 2021. 
  6. 6.0 6.1 6.2 6.3 Adigun, Sunday (3 September 2018). "How My Curvy Shape Has Boosted My Movie Career – Star Actress, NKECHI BLESSING". City People Magazine. Retrieved 8 May 2021. 
  7. Daniel, Eniola (February 2017). "Nigeria Carnival USA gets ambassadors". guardian.ng. Archived from the original on 8 May 2021. Retrieved 8 May 2021. 
  8. People, City (24 September 2018). "Winners Emerge @ 2018 City People Movie Awards". City People Magazine. Retrieved 7 May 2021. 
  9. "Actress, Nkechi Blessing, Seun Jimoh unveiled as hosts of African Entertainment Awards USA 2020". Vanguard News. 16 December 2020. Retrieved 7 May 2021. 
  10. "Toyin Abraham features Sanyeri, Broda Shaggi in 'Fate of Alakada: The Party Planner'". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 December 2019. Retrieved 7 May 2021. 
  11. 11.0 11.1 Yinka, Ade (10 June 2021). "Nkechi Blessing finally shares wedding photos with her politician boyfriend". Kemi Filani. Retrieved 29 September 2021. 
  12. "How my mother died of stomach pain: Actress Nkechi Blessing mourns - P.M. News". P.M. News. Retrieved 29 September 2021. 
  13. "The Reason Why Nkechi Blessing and Her Husband Falegan Broke up". 
  14. "Nkechi Blessing Sunday Set To Release An Islamic Movie "Amerah"". TRYBE Movie Channel (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 30 November 2020. Archived from the original on 8 May 2021. Retrieved 8 May 2021.