Nkhensani Manganyi
Ìrísí
Nkhensani Manganyi jẹ́ òṣèré àti aránṣọ ni orílẹ̀-èdè South Africa.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2000, Manganyi bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ aránṣọ tirẹ̀ tí ó pè ní Stoned Cherrie.[1][2] Ìkan lára àwọn aṣọ tí ó rán gbáyi láti ilé iṣẹ́ ìròyìn Drum.[3] Ilẹ̀ iṣẹ́ náà má ń ṣe gíláàsì fún ojú[4]. Díè nínú àwọn iṣẹ́ rẹ sì wà ní Fashion Institute of Technology níbi tí won tí se ìfihàn rẹ níbi ayẹyẹ Black Fashion Designers ni ọdún 2016[5][6]. Manganyi tí kópa nínú àwọn eré bíi Legend of the Hidden City, Tarzan, The Epic Adventures ati Kickboxer 5 àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ọdún 2003, ó se adájọ́ fún ètò Pop Star tí won ṣẹ́ lórílẹ̀ èdè South Africa.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Mariam Jooma (2003-10-14). "South African Protest Songs Find Different Themes". Boston Globe. http://www.boston.com/ae/music/articles/2003/10/14/south_african_protest_songs_find_different_themes/.
- ↑ "Africa Fashion Week – Day 1". Bella Naija. 2006-08-08.
- ↑ Simon Robinson (2004-04-11). "That's Kwaito Style". Time magazine. Archived from the original on 2010-05-16. https://web.archive.org/web/20100516175357/http://www.time.com/time/europe/html/040419/kwaito.html.
- ↑ "Winning Women: Renaissance fashion guru". News24. http://www.news24.com/Archives/City-Press/Winning-Women-Renaissance-fashion-guru-20150430.
- ↑ Peoples, Lindsay. "Black Designers Finally Get a Museum Exhibit" (in en). The Cut. http://nymag.com/thecut/2016/12/black-designers-finally-get-a-museum-exhibit.html.
- ↑ "Black Fashion Designers | Fashion Institute of Technology". www.fitnyc.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-03-09.