Nneka (àkọrin)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nneka
Nneka ní Cargo, London ní ọdún 2009
Nneka ní Cargo, London ní ọdún 2009
Background information
Orúkọ àbísọNneka Lucia Egbuna
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kejìlá 1980 (1980-12-24) (ọmọ ọdún 43)
Ìbẹ̀rẹ̀Warri, Nàìjíríà
Irú orinR&B, hip hop, soul, afrobeat, reggae
Occupation(s)Singer, songwriter, actress
InstrumentsVocals, guitars, drums, piano
Years active2003–present
LabelsYo Mama's Recording, Sony Music, Epic Records, Decon Records
Websitennekaworld.com

Nneka Lucia Egbuna (tí a bí ní ọjọ́ kẹríndínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1980[1]) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrin àti òṣèré bìnrin. Ó ma ń kọrin ní, Èdè Gẹ̀ẹ́sì, Igbo àti èdè Pidgin Nàìjíríà.

Ìpìlẹ̀ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Nneka Lucia Egbuna ní Warri, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, Nàìjíríà, a sì tọ dàgbà ní ìlú kan náà, ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀ ède Jẹ́mánì, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2][3] Òun ni àbíkẹ́yìn nínú ọmọ mẹ́rin. Nígbà tí Nneka jẹ́ ọmọ ọdún méjì, ìyá rẹ̀ fi bàbá rẹ̀ sílè. Nígbà tí bàbá rẹ̀ fẹ́ ìyàwó míràn, ìyàwó tuntun yìí fi ìyà jẹ àwọn ọmọ ìyàwó àkọ́kọ́, pàápàá jùlọ àwọn ọmọ méjì tí ó jẹ́ àbíkẹ́yìn—Nneka àti ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ọkùnrin, Anato.[1]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Steffes-Halmer, Annabelle (18 December 2017). "After the escape: how Nneka Egbuna found a home in music". Deutsche Welle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 5 February 2021. 
  2. "Biography". Nneka World (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 January 2023. 
  3. "Nneka talks about her lighter side on new album My Fairy Tales". National Public Radio. Retrieved 20 January 2023.