Nomalanga Shozi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nomalanga Shozi
Ọjọ́ìbíJessica Nomalanga Shozi
Ọjọ́ Kejìlá oṣù kéje, ọdún 1994
Orílẹ̀-èdèSouth Africa
Orúkọ mírànThe Flame
Ẹ̀kọ́Marburg Secondary School, Rosebank College
Iṣẹ́Olùṣètò tẹlẹfísọ̀n àti rédìó , Òṣèré
EmployerViacom, Gagasi FM
Gbajúmọ̀ fúnThe Face Of BET Africa

Jessica Nomalanga Shozi (wọ́n bi ni ọdún1994) jẹ́ òṣèré South African, díjè rẹ́dìó àti ènìyàn tó máa ń ṣe àfihàn lórí tẹlẹfísàn. Ó ṣe àfihàn lórí the soap Rhythm City àti MTV Shuga Alone Together bẹ́ẹ̀ náà ló ti jẹ́ olóòtú fún BET Africa

Ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Shozi ni ọdún1994 àti wí pé ó dàgbà sókè ní Port Shepstone níbi tí ó ti ní ìbátan méjìlá. Ó kẹ́kọ̀ọ́ ni Marburg Sẹ́kọ́ndárí sukùlù àti Rosebank Kọlẹ̀jì.[1] Ó parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ pẹ̀lú Public Relations. Ó ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bí díjè rẹ́díò.[2]

Shozi di ẹni mọ́mọ̀ nígbà tí ó darapọ̀ mọ́ eré-ẹlẹ́sẹṣẹ e.tv Rhythm City. Ó yege lára àwọn ènìyàn tọ́ mú fún ìdánwò gbangba tí àwọn ènìyàn 5000 fi orúkọ wọ́n lè lórí èrò ayélujára. Òun ni wọ́n wí pé kí ó kó ìpa ẹni tí wọ́n fi sọ eré Normalanga. Ẹ̀dá ìtàn tuntun tí bàbá rẹ̀ jẹ́ ògbọ́ǹtarìgì òṣìṣẹ́ ọlọ́lá.[2]

Ó lọ sí Las Vegas láti ṣe kọ́và báákísitààjì àti rẹ́dí katì ti ọdún 2018 "BET Soul Train Awards" àti ní oṣù kọkọ̀nla ni ọdún 2018 Wọ́n kéde wí pé òun ló má jẹ́ olóòtú fún BET Breaks - ètò magazínìì tuntun made in, àti nípa Adúláwò.[3] Ní ọdún 2020 Ó hàn gẹ́gẹ́ bí Mbali ní MTV Shuga's[4] Alone Together tó ṣe àwọn àfihàn àléébù àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 pandemic. Tí eré náà jẹ́ kíkọ láti ọwọ́ Tunde Aladese atiy Nkiru Njoku.[5] àti tó kéde káàkiri fún ọjó àádọ́rin - tí ọkàn lára àwọn tó ṣègbé lẹ́yìn fún eré náà jẹ́ United Nations.[6] Tí wọ́n ṣe eré-ẹlẹ́sẹsẹ náà ni Nàìjíríà, South Africa, Kẹ̀ńyà àti Côte d'Ivoire àti wí pé eré náà ma jẹ́ àlàyé ọ̀rọ̀ tó wàyé láàárín àwọn ẹ̀dá ìtàn náà ní orí èrò ayélujára. Gbogbo ìṣe eré náà jẹ́ ṣíṣe láti ọwọ́ àwọn òṣèré tó kópa nínu eré náà.[7] Mohau Cele, Lerato Walaza àti Jemima Osunde wà nínu eré náà.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Gitonga, Ruth (2020-08-11). "Who is Nomalanga Shozi? All amazing facts about the actress". Briefly (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-22. 
  2. 2.0 2.1 Makhele, Tshepiso. "Rhythm City has found Nomalanga". The Citizen (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-22. 
  3. Mkhize, Lesego. "Nomalanga Shozi on becoming the new face of BET in Africa: ‘It’s such an honour’". Drum (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-08-22. 
  4. "MOHALE JOINS MTV SHUGA Digital Series". DailySun. Retrieved 2020-08-22. 
  5. "MTV Shuga: Alone Together | Episode 52". YouTube. 21 July 2020. Retrieved 23 August 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "Every Woman Every Child partners with the MTV Staying Alive Foundation to Tackle COVID-19". Every Woman Every Child (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-16. Archived from the original on 2021-10-09. Retrieved 2020-04-30. 
  7. Akabogu, Njideka (2020-04-16). "MTV Shuga and ViacomCBS Africa Respond to COVID-19 with "Alone Together" Online Series". BHM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-30.