Jemima Osunde
Jemima Osunde | |
---|---|
Osunde appearing on an episode of NdaniTV's Real Talk | |
Ọjọ́ìbí | April 30 1996 (age 24) Lagos, Lagos State, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | |
Gbajúmọ̀ fún | Shuga |
Website | Official website |
Jemima Osunde tí wọ́n bí ní ọgbọ̀njọ́ oṣù Kẹrin ọdún 1996. [1] jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé , model àti olóòtú ètò lórí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán Ọmo orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[2] Ó di ìlú-mòọ́ká lẹ́yìn tí í ó kópa gẹ́gẹ́ bí ẹ̀dá-ìtàn "Jemima" nínú eré àtìgbà-dégbà onípele ti Shuga.[3]Wọ́n yan Osunde fún amì-ẹ̀yẹ ti Best Actress in a Leading Role àyẹyẹ 15th Africa Movie Academy Awards ẹlẹ́kẹẹ̀ẹ́dógún irú rẹ̀ tí yóò wáyé fún ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré The Delivery Boy (2018).[4]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Osunde sí ìlú Edo, ó kẹ́kọ̀ọ́ nípa physiotherapy ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Ìpínlẹ̀ Èkó.[5][6][7]Ó kópa nínú eré Jungle Jewel lẹ́yìn tí àbúrò bàbá rẹ̀ gbàá níyànjú láti máa lọ ṣeré ìtàgé.
Ó kópa bí ẹ̀dá-ìtàn "Laila" nínú eré àtìgbà-dégbà onípele ti MTV Shuga.Ó pa ìkópa tì nínú eré yí nígbà tí wọ́n gbé eré náà lọ sí orílẹ̀-èdè South Africa, àmọ́ ó tún bá wọn kópa padà nígba tí eré náà padà sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [8] Ní ọdún 2018, ó kópa nínú eré Rumour Has it pẹ̀lú òṣèré mìíràn bíi: Linda Ejiofor lórí NdaniTV's .[9][10]
Osunde tún báwọn kópa nínú ìpele keje lórí MTV Shuga lásìkò ìsémólé COVID-9 .[11][12].
Ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2019, Osund jáde ẹ̀kọ́ nílé ẹ̀kọ́ Yunifásitì Èkó nínú ìmọ̀ physiotherapy.[13]
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Jungle Jewel
- Esohe
- Stella (2016)
- My Wife & I (2017)
- Isoken (2017)
- New Money (2018)
- Lionheart (2018)
- New Money (2018)
- The Delivery Boy (2018)
Àwọn eré amóhù-máwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Shuga
- This Is It (2016–2017)
- Rumour Has It (2018)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Birthday Girl Jemima Osunde is Painting the Town Red from her Couch". BellaNaija. 30 April 2020. Retrieved 30 April 2020.
- ↑ "Jemima Osunde biography, age and lifestyle" (in en). Uzomedia TV Youtube. https://www.youtube.com/watch?v=frDdos2Ic_s.
- ↑ "I'm a no nonense person – Jemima Osunde".
- ↑ Shaibu Husseini (28 September 2019). "AMAA 2019 nomination: Four ‘huge’ slots for Nollywood’s leading ladies". Guardian Life. Archived from the original on 23 October 2020. Retrieved 30 April 2020.
- ↑ "A Brief Spotlight On Genevieve Nnaji’s Amazing ‘Lookalike’, Jemima Osunde". Archived from the original on 2018-06-27. Retrieved 2020-10-29.
- ↑ "Budding actress, Jemima Osunde up against Adesua Etomi?".
- ↑ "Actress is what Nigeria needs at this time". Archived from the original on 2018-07-28. Retrieved 2020-10-29.
- ↑ Obioha, Ikenna (7 Jan 2018). "How I got global fame – Jemima Osunde, actress". The Sun. http://sunnewsonline.com/how-i-got-global-fame-jemima-osunde-actress/.
- ↑ NdaniTV (2018-03-14), Go Behind The Scenes of Rumour Has It Season 2, retrieved 2018-03-15
- ↑ NdaniTV (2018-04-20), Rumour Has It S2E5: Janus, retrieved 2018-04-23
- ↑ "MTV Shuga: Alone Together | Episode 7". YouTube MTV Shuga. 20 April 2020. Retrieved 29 April 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Akabogu, Njideka (2020-04-16). "MTV Shuga and ViacomCBS Africa Respond to COVID-19 with "Alone Together" Online Series". BHM (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-04-30.
- ↑ Odion Okonofua (March 28, 2019). "Jemima Osunde graduates from medical school". Pulse Nigeria. Retrieved 25 January 2020.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Jemima Osunde |
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Pages with citations using unsupported parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Year of birth missing (living people)
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Actresses from Edo State
- Nigerian television actresses
- Nigerian film actresses
- University of Lagos alumni
- 21st-century Nigerian actresses