Jump to content

Nwebonyi Onyeka Peter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Nwebonyi Onyeka Peter jẹ́ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. Lọwọlọwọ o n ṣiṣẹ gẹgẹbi Aṣoju ton nsójú àgbègbè Ebonyi North ni Ile-igbimọ Aṣofin Agba kẹwàá abẹ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressive Congress (APC). O tun di ipo Igbákejì Oloye olopa ilẹ̀ ìgbìmọ̀ aṣòfin.[1] [2] [3]