Oba Saheed Ademola Elegushi
Ìrísí
Kabiesi, Oba Alayeluwa Saheed Ademola Elegushi, Kusenla III, ara oba ileYoruba ni Naijiria (won bi ni 10 Osu kerin 1976), ohun ni okan le logun Elegushi ti ile ilu Ikate-Elegushi.[1] Oba Elegushi je omo oba idile Kusenla ti ilu Ikate ni ipinle Eko. O gbade leyin ipakoda baba e, iyen Oba Yekini Adeniyi Elegushi, Oba Ogun ti ilu Elegushi Ikate ti o wa ni ori oye larin odun 1991 si odun 2009.[2] Oba Elegushi gba opa ase lowo ijoba ipinle Eko Lagos State ni 27 Osu Kerin, Odun 2010. Oba Elegushi sise fun ijoba ipinle Eko ni aye oludamoran pataki ati oludamoran agba fun ijoba Bola Tinubu ati Babatunde Fashola, ki oto di Oba alade.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "In pictures: Country of kings, Nigeria's many monarchs". BBC News. 13 October 2013. https://www.bbc.com/news/world-africa-24492437.
- ↑ "Oba Elegushi remembers dad". The Nation. 24 November 2019. https://thenationonlineng.net/oba-elegushi-remembers-dad/.
- ↑ Temitope Oyefeso (27 April 2020). "Elegushi: Celebrating a decade of royal excellence". PM News. https://www.pmnewsnigeria.com/2020/04/27/elegushi-celebrating-a-decade-of-royal-excellence/.