Jump to content

Odò Apies

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Odò Apies
odò
mouth of the watercoursePienaars River Àtúnṣe
drainage basinLimpopo basin Àtúnṣe
orílè-èdèGúúsù Áfríkà Àtúnṣe
Ìjoba ìbílèGauteng Àtúnṣe
coordinate location25°44′0″S 28°11′5″E, 25°37′21″S 28°11′29″E, 25°10′25″S 28°6′38″E Àtúnṣe

Odò Apies jẹ́ odò kan tí ó sàn kọjá Pretoria, orílẹ̀ èdè South Africa. Orísun rẹ̀ jẹ́ láti gúúsù Erasmus Park) ó sì ṣàn lọ ọ̀nà àríwá títí tí ó fi sàn wọnú Pienaars River.[1]

"Apies" tún mọ̀ sí àwọn ọ̀bọ kékeré ní èdè Afrikani, wọ́n sì fun lórúko yìí nítorí àwọn ọ̀bọ tí ó ma ń wà ní etí odò Apies.

Ìlú Mamelodi rí orúkọ rẹ̀ láti ara odò náà, orúkọ ìlú náà ni "Mamelodi ya Tshwane", tí ó túmọ̀ sí "afon fèrè Apies River".[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Gauteng State of the Environment Report 2004" (PDF). Gauteng Provincial Government. p. 4. Archived from the original (PDF) on 2016-01-21. Retrieved 2009-01-27.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "Meanings of place names in South Africa". africanlanguages.com. Archived from the original on 3 February 2009. Retrieved 2009-01-27.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)