Odolaye Aremu
Ìrísí
Odolaye Aremu Mohammodu Odolaye Aremu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ilorin |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Ilorin |
Irú orin | Dadakuada |
Occupation(s) | Folk musician, Praise singer |
Instruments | Gangan, Bata Talking Drum |
Labels | Olatubosun Records |
Mohammodu Odolaye Aremu je omo bibi ilu Ilorin, olorin Dadakuada ti o korin ni opolopo ilu Yoruba ti o si se awo orin pupo sile titi o fi ku lodun 1997. [1] Nigba aye re, o ti gbe ni opolopo agbegbe pẹlu Ibadan, Ilorin, Abeokuta, Okeho, Shaki ati Eko. Sugbon, o lo opolopo akoko re ni ilu Ibadan.
Iṣẹ iṣe orin
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gẹ́gẹ́ bí ọ̀pọ̀ àwọn olórin Yorùbá, ó kọrin ìyìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn pàtàkì àti olókìkí láwùjọ. Eyi pẹlu Dokita Olusola Saraki, Oloye Alhaji Abdul-Azeez Arisekola Alao ; Alhaji Jimoh Saro, Chief Meredith Adisa Akinloye, Oba Lamidi Adeyemi Olayiwola III, Chief Ladoke Akintola, Ariyibi Adedibu and many others. [2][3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.routledge.com/Yoruba-Oral-Tradition-in-Islamic-Nigeria-A-History-of-Dadakuada/NaAllah/p/book/9780367787950
- ↑ "Nigeria: Arisekola-Alao - Exit of Quintessential Ibadan Man". Daily Independent. 21 Jun 2014. Archived on 3 Feb 2021. Error: If you specify
|archivedate=
, you must also specify|archiveurl=
. https://allafrica.com/stories/201406230215.html. - ↑ https://allafrica.com/stories/201406230215.html