Ohun àpòpọ̀ògùn
Ìrísí
Kẹ́míkà (chemical substance) je ohunkohun to je elo to wa layika wa ati kakiri agbalaye ti a n ko ninu eko Chemistry. A le lo tabi da "kemika" pelu awon igbese ninu kemistri. A le pe wo ni apilese tabi adapo. Bi bayi kemika ni an pe gbogbo ohun elo to ni idamo pato bi fun apere irin, iyọ̀, sugar, epo, kerosine, ogógóró ati bebe lo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |