Ohun àpòpọ̀ògùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ohun kẹ́míkà)
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Omi ati oru omi je iru otooto meji kemika kanna.

Kẹ́míkà (chemical substance) je ohunkohun to je elo to wa layika wa ati kakiri agbalaye ti a n ko ninu eko Kemistri. A le lo tabi da "kemika" pelu awon igbese ninu kemistri. A le pe wo ni apilese tabi adapo. Bi bayi kemika ni an pe gbogbo ohun elo to ni idamo pato bi fun apere irin, iyo, suga, epo, Parafinni, oti ati bebe lo.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]