Olajide Olatubosun
Ìrísí
Olajide Olatubosun je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. O je ọmọ ile ìgbìmọ̀ asoju ìjọba àpapọ̀ to n soju àgbègbè Saki East / Saki West / Atisbo ti Ìpínlẹ̀ Oyo ni ile igbimo asofin agba kẹsàn-án. [1] [2] [3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://insideoyo.com/inec-declares-apcs-olajide-olatunbosun-winner-of-atisbo-saki-east-saki-west-federal-constituency/
- ↑ https://dailypost.ng/2019/06/02/9th-assembly-speaker-ill-fight-blood-apc-rep-dares-party-gbajabiamilas-choice/
- ↑ https://tribuneonlineng.com/covid-19-reps-member-olatubosun-gives-palliatives-urges-sacrifice-at-easter/