Olajumoke Adenowo
Olajumoke Adenowo | |
---|---|
Ilẹ̀abínibí | Nàìjíríà |
Training | BSc Hons Architecture [1988], Masters in Architecture [1991] at Obafemi Awolowo University, Chief Executive Programme [CEP] Lagos Business School [2002] |
Ọlájùmọ̀kẹ́ Adénọ́wọ̀ tí a bí ní ojó kerindinlogun, osù kewa, odun 1968(16 October, 1968) jé ayaworan ilé(architect) omo bíbi orílè-èdè Nàìjíríà. Obere ilé isé tí ó ún yáwòrán ilé tí ósì ún se inú ilé loso rè ní odun 1994, orúko ilé isé náà ní "AD consulting". [1]. Orúko oko rè ni Olukorede Adenowo, wón bí omokurin méjì [2]
Àárò ayé àti èkó re
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abí Ọlájùmọ̀kẹ́ Adénọ́wọ̀ sí ìlú Ibadan, ìpinlè Oyo ni orílè-èdè Nàìjíríà, àwon òbí rè méjèjì jé òjògbón, bàbá rè jé ojogbon ninú ìtàn, ìyá rè sì jé ojogbon ninú criminology [3]. Ógbé nínú ogbà Yunifásitì ti Obafemi Awolowo. Obere ìwé kika ní yunifásitì náà nígbanígbà tí ó jé omo odun merinla, ósì keko gboye nínú imo sayensi pèlú eye nínú ìmò iyaworan ilé(Architecture) léyìn odun marun. Ó tèsíwájú si láti àmì-èye master ní iyaworan ilé ní yunifásitì kanáà [4]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "About Us". Home. Archived from the original on 2022-03-28. Retrieved 2022-03-30.
- ↑ "I compete against myself - Olajumoke Adenowo". News Fetchers. 2013-12-21. Retrieved 2022-03-30.
- ↑ "Olajumoke Adenowo". PR2J3C4 - Nigeria @ Her Best. 2017-01-31. Archived from the original on 2021-11-24. Retrieved 2022-03-30.
- ↑ Nojimu-Yusuf, Sinmisola (2016-08-16). "Olajumoke Adenowo". Sinmisola Nojimu-Yusuf. Archived from the original on 2021-11-29. Retrieved 2022-03-30.