Olajumoke Bodunrin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Olajumoke Bodunrin
Òrọ̀ ẹni
Ọjọ́ìbí7 Oṣù Kejì 1945 (1945-02-07) (ọmọ ọdún 79)
Odo-Asanyin, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Nàìjíríà[1]
Height1.52 m (4 ft 12 in)
Weight44 kg (97 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáEléré-ìdárayá
Event(s)100 m, 400 m
Achievements and titles
Personal best(s)100 m – 11.71 (1968)
400 m – 56.1 (1968)[1]

Olajumoke Bodunrin, ( tí wọn bi ní ọjọ́ kèje, oṣù kejì, ọdún 1945) ti gba ìsinmi gẹ́gẹ́ bí i eléré-ìdárayá ti ilẹ̀ Nàìjíríà,[2] Òun ni wọ́n pè ní ''obìrin Africa tí ó yára jùlọ nínú eré-sísá'', nígbà eré-sísá rẹ̀.[3] Olajumoke gba góòlù ní All-Africa Games,1965, ní Brazzaville, Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò, kí ó tó lọ ṣojú ilè Nàìjíríà ní Summer Olympics, ti 1968, ní Mẹ́ksíkò.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Olajumoke Bodunrin. Sports Reference
  2. "Olajumoke Bodunrin". FanBase. Retrieved 13 September 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. "The Death of Nigerian Sports And A Walk Down Memory Lane". Nigerian Muse. 22 August 2009. Retrieved 13 September 2015. 
  4. "1968 Olympic Games". Sports Bank. Retrieved 13 September 2015. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]