Jump to content

Old Towns of Djenné

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Infobox ancient site

Ìlú Old Towns of Djenné jẹ́ ílú tí èrò pọ̀ sí gidi tí ó wà ní Djenné, ní orílẹ̀-èdè Mali. Àwọn ibi mẹ́rin kan wà nílú yí tí wọ́ n ń gbé ìlú yí níyì, àwọn ni: Djenné-Djeno, Hambarkétolo, Kaniana àti Tonomba. Ọdún 1988 ni àjọ UNESCO fi ìlú yí sí abẹ́ ìbojúwò wọn ni World Heritage list.[1]

Àwọn ará Djenné ti ń gbé ìlú wọn láti nkan bí ọdún 250 B.C., Ìlú yí tún di ojú ọjà àti ojúkò pàtàkì fún àwọn olùta góòlù. Ní ọ̀rùndún kẹẹ̀dógún sí ìkẹrìndínlógún sẹ́yìn, ìlú yí jẹ́ ibi tí ẹ̀sìn Islam ti gbilẹ̀ dára dára tí àwọn ènìyàn sì ń kọ́ nípa ẹ̀sìn náà níbẹ̀. Púpọ̀ àwọn ilé àtjọ́ tí wọ́n tó ẹgbẹ̀rún méjì tí wọ́n fi àpáta kọ́ ni wọ́n ṣì wà ní ìdúró títí di òní àwọn ilé náà ni wọ́n pè ní (toguere). Wọ́n kọ́ àwọn ilé náà láti fi dẹ́kun ìṣẹ̀lẹ̀ omíyalé ni .[1]

Àdàkọ:Free-content attribution

ÀWọn ìtọ́la sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Centre, UNESCO World Heritage. "Old Towns of Djenné". UNESCO World Heritage Centre (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-22.