Olota of Ota
Ọlọ́tà ti ìlú Ọ̀tà jẹ́ adarí ìbílẹ̀ ìlú náà tí ó sì ní àgbàrá láti jọba lé àwọn ará ìlúỌ̀tà lórí , Ìpínlẹ̀ Ogun,Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà .
Ilé iṣẹ́ ìbílẹ̀ tó wà ní Ọ̀TÀ ti kọ́kọ́ wá láti IFẸ̀ OÒDÁYÉ tàbí Ọ̀RÚNMÌLÀ pàápàá bí Ọ̀RÚNMÌLÀ, IFA ńlá ṣe pàdé obìnrin OBA kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ IYARIGIMOKO OTAYO, tí a fún ní OLOTA ODO, OBA ARODEDEWOMI òun ni ẹni tí ó bí Ọ̀TÀ òun sì ni ìyá tí ó bi i gan ní pàtó òun sì ni ỌLỌ́TÀ àkọ́kọ́ tí ó ti wà nínú ìtàn láti ayé bá yé tí ODÙ-IFÁ sì fi hàn kedegbe tí à ń pè é ní IRET ỌLỌ́TÀ (Ọ̀WỌ́NRÍN) and OSA MÉJÌ (ODU ELEYE). Síbẹsíbẹ̀ àwọn àṣà yìí kò fìdí múlẹ̀ nìkan ní Ọ̀TÀ ṣùgbọ́n púpọ̀ nínú àwọn ìtàn ilẹ̀ Yorùbá pàápàá jù lọ àwọn aṣojú IFA tí ń jẹ́ (babalawo) láàárín ìlú Ọ̀TÀ àti ní èyí tí kìí ṣe inú ìlú Ọ̀TÀ àti díẹ̀ nínú àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n àti àwọn oní wádìí tún fi ìdí kan náà múlẹ̀ tí ó sì báamu. Báyìí ni IYARIGIMOKO jẹ́ ỌLỌ́TÀ àkọ́kọ́ (OBA) nínú ìtàn eléyìí tí ó wà títí di àkókò BC ó kéré jù bí a ti fi ìdí rẹ múlẹ̀ nínú àwọn àṣà ti Odù-ifá tí a mẹ́nubà lókè. Arábìnrin yìí tún ti jẹ́ ATELÉ OLÓDE MÈRÒ, ERELÚ AFÍNJÚ ỌLỌ́JÀ ẸKÙN èyí tí a mọ̀ sí ỌLỌ́TÀ ELÉGBÈJÉ ỌJÀ àti ỌLỌ́TÀ ỌLỌ́FIN ARAÒYE, ọkùnrin àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ jẹ́ dárí ìlú ṣùgbọ́n ó jẹ́ ọkùnrin ẹlẹ́ẹ̀kẹ́rin tí ỌLỌ́TÀ tí ó jọba ní Ọ̀TÀ tí kò sì sí déètì kan pàtó, bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn Ọba tí ó tún jẹ lẹ́yìn rẹ̀ (Ọlọ́fin ARAÒYE) kò sí ọjọ́ kan tàbí déètì kan pàtó fún wọn tí ó wà ní àkọsílẹ̀. Oríṣiríṣi Ọba mìíràn ni ó wà ní Ọ̀TÀ tí àwọn orúkọ àti ìjọba wọn ti parẹ nípasẹ̀ dòjé àkókò, àti/tàbí pé kò ṣe é rántí mọ́ nítorí àkókò náà ṣùgbọ́n díẹ̀ nínú wọn ni ó tún wà ní ìrántí.
ODELU FAGBA ti idile ti gbogbo eniyan mo si ni Olota ki Oba Osolo (OLOFIN) to wa bayii ti osolo funra re dari ki o to lkoriku. ARUGBA -IFA, OLOFIN IFA obinrin alagbara ni ogbehin ODELU-FAGBBA. ARUGBA IFA ni won bi ni OTA si opin orundun 13th. Arugbaifa, an OTA AWORI woman took IFA ikin (IFA ELEKURO), to Oyo ILE the type Orunmila used during his life time which now every successive Alaafin of Oyo adopted as well as the Oyo mesi known till date. She later married Alaafin Oluaso (circa 1300-1350) and was the mother of Alaafin ONIGBOGI, OLOFIN AREMITAN, the founder of ILE-OLUJI and prince Koyi, the founder of ADO-AWAYE in lbarapa land. Inconsequent of the above, gbogbo Alaafin ti Oyo ati awon agba Oyo ka Otta gege bi ile iya won.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]1. ^ PC Lloyd (1962). Ofin Ile Yoruba. Oxford University Tẹ. p. 225.
2. ^ Lọ soke si: a b Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co.p. 15.
3. ^ Lọ soke si: a b Ruhollah Ajibola Salako (1999). Ota: The Biography of the Foremost Awori Town. Penink & Co.p. 16.
4. ^ Up up to: a b "Lagos je ti Awori, Bini pade won nibe - Akintoye". Awọn iwe iroyin Punch. Oṣu kejila ọjọ 17, ọdun 2017. Ti gba pada 28 Oṣu Kini 2023.
5. ^ Lọ soke si: a b "Itan, oran eniyan". The Guardian Nigeria. 11 Oṣu Karun ọdun 2017. Ti gba pada 28 Oṣu Kini 2023.
6. ^ Jump up to: a b Akintoye, Stephen Adebanji (1 January 2010). Itan Awon Yoruba. Amalion Publishing. ISBN 978-2-35926-027-4 .
7. ^ “AWON BABA WA Pelu OLOTA – IFA PRIEST”. Ti gba pada 28 Oṣu Kini 2023.
8. ^ Fo soke si: a b c "Masquerading Iselu". Indiana University Tẹ. Ti gba pada 28 Oṣu Kini ọdun 2023.
9. ^ Jump up to: a b "Irete Owonrin - UCLA Library Digital Collections". ucla.edu. Ti gba pada 28 Oṣu Kini 2023.