Olúbàdàn
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Olubadan)
Olubadan ni oruko oye oba ilu ibadan. Olubadan to wa lori oye lowolowo bayii (ni 2016) ni Sálíù Adétúnjí.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |