Olufemi Terry
Olufemi Terry | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | Sierra Leone |
Iṣẹ́ | Writer, journalist |
Subject | African diaspora |
Notable works | "Stickfighting Days", The Sum of All Losses |
Notable awards | Caine Prize for African Writing (2010) |
Olufemi Terry jẹ́ òǹkọ́wé ara Sierra Leone. Ó gba ẹ̀bùn Caine Prize for African Writing ti ọdún 2010 fún ìwé kékeré ẹlẹ́ẹ̀kejì rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Stickfighting Days," èyí tí wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀ jáde ní Chimurenga.[1] Àwọn adájọ́ náà sọ pé ó jẹ́ "tálẹ̀ǹti kan pẹ̀lú ọjọ́-iwájú tó dára".[2] Ó lérò láti ṣàtẹ̀jáde ìwé kejì láìpẹ́.
Ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Terry sí ìlú Siẹrra Léònè, àmọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan àti Côte d'Ivoire ni ó dàgbà sí, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ ní New York, United States,[3] kí ó tó di akọ̀ròyìn ní Somalia àti Uganda.[4] Ìlú Stuttgart, ní Germany ló ń gbé báyìí.[3] Ó gboyè MA nínú ẹ̀kọ́ creative writing ní University of Cape Town ní ọdún 2008.[5]
Ní 5 July 2010, Terry gba ẹ̀bùn Caine Prize fún African Writing, ṣị́wájú àwọn òǹkọ̀wé ilè Afirika mìíràn bí i Ken Barris (South Africa), Lily Mabura (Kenya), Namwali Serpell (Zambia), àti Alex Smith (South Africa).[6][7]
Terry sọ ọ́ di mímọ̀ pé "ìyàlẹ́nu bọ òun fún wákàtí kan àkọ́kọ́". Ó gba ẹ̀bùn £10,000 ní London.[4] Ó sì tún le lo oṣù kan ní Georgetown University, ní United States.[4]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- "Stickfighting Days". The Guardian (London). 6 July 2010. https://www.theguardian.com/books/interactive/2010/jul/06/stickfighting-olufemi-terry.
- "Losing Labels". BBC Focus on Africa Magazine Vol. 21. October 2010. Archived from the original on 2012-03-18. https://web.archive.org/web/20120318073031/http://www.exacteditions.com/exact/browse/538/730/7674/3/3.
- "Austerity not ostentation". The Africa Report. 9 February 2011. Archived from the original on 21 July 2011. https://web.archive.org/web/20110721091736/http://www.theafricareport.com/archives2/opinion/5136470-last-word-by-olufemi-terry-we-need-austerity-not-ostentation.html.
- "Lamu Squat". Guernica. 1 March 2011. Archived from the original on 25 March 2012. https://web.archive.org/web/20120325044249/http://www.guernicamag.com/fiction/2408/terry_3_1_11/.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Flood, Alison (6 July 2010). "Olufemi Terry wins Caine prize for African writing". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/books/2010/jul/06/olufemi-terry-wins-caine-prize. Retrieved 6 July 2010. "Mormegil is as long as our regulations allow, a lovely willow poke, dark willow – that's why I chose the name. It means black sword in Tolkien's language. – Quote from "Stickfighting Days""
- ↑ "Sierra Leone's Olufemi Terry wins Caine writing prize". BBC News (BBC). 6 July 2010. http://news.bbc.co.uk/2/hi/world/africa/10519045.stm. Retrieved 6 July 2010.
- ↑ 3.0 3.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedSierra Leone's Olufemi Terry wins Caine writing prize2
- ↑ 4.0 4.1 4.2 "African literary prize goes to Cape Town writer". CBC News. 6 July 2010. http://www.cbc.ca/arts/books/story/2010/07/06/caine-prize-african-writing.html?ref=rss. Retrieved 6 July 2010.
- ↑ Ogunlesi, Tolu (7 July 2010). "Olufemi Terry wins 2010 Caine Prize for African Writing". NEXT. http://234next.com/csp/cms/sites/Next/ArtsandCulture/5590567-147/story.csp. Retrieved 7 July 2010.
- ↑ Frenette, Brad (6 July 2010). "Olufemi Terry wins 2010 Caine Prize". National Post (Canwest). http://arts.nationalpost.com/2010/07/06/olufemi-terry-wins-caine-prize/. Retrieved 6 July 2010.
- ↑ Flood, Alison (6 July 2010). "Olufemi Terry wins Caine prize for African writing". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/books/2010/jul/06/olufemi-terry-wins-caine-prize.