Omi Omú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Omi Omú(tí àwon ènìyàn tún mò sí "Omi Oyàn) jé omi tí a ti inú omú se jáde. Omi omú jé orisun gboogi okun fún omo titun, o sì ní gbogbo nkan tí omo nílò láti dagba ninú, awon bi omi, carbohydrate, aramuaradagba àti òrá[1]

. Omi omú sì tún ní àwon eroja to leon bàrùn to bá wonu ara omo jà, omi omú ní òpòlopò aafanàwon woAjọ Eleto IlerAgbaye sí parowa pé tí ìyá omo fún omo titun ni omi omú nikan fún osù mefa akoko láì fun ní ounje mirán[2

wón sì tún parowa pé kí ìyá fún omo ní omi omú fún okere jù, odún meji.

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Breast Milk Composition Over Time: What's in it and How Does it Change?". Family & Co. Nutrition. 2021-05-03. Retrieved 2022-02-26. 
  2. "Breastfeeding". WHO. 2019-11-11. Retrieved 2022-02-26.