Onos Ariyo

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Onos Ariyo
Orúkọ àbísọOnoriode Ebiere Bikawei
Irú orin
Occupation(s)Singer, songwriter
Years active2009–present
LabelsMirus
Associated actsNikki Laoye, Glowreeyah Briamah, Sammie Okposo, Wilson Joel

Onoriode Ebiere Ariyo tí a mọ̀ sí Onos Ariyo jẹ́ akọrin àti akọrin tí ó da lórílẹ̀ ẹ̀dẹ̀ Nàìjíríà. A mọ̀ ọ́n jùlọ sí orin ìyìn rẹ̀ “Alagbara” tí ó jẹ́ àkórí Orin tí ọ kọ tí Ọ̀gbẹ́ni Wilson Joel bá a jẹ́ agbéjáde rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Ni Oṣù Kẹsàn án ọdún 2018, o jẹ́ ẹni Kan tí a dárúkọ lára àwọn tí o jẹ́ gbajúmọ̀ àti àwọn tí ọ jẹ́ ìkíní títí dé ti ọgọ́rùn ún Àwọn ènìyàn ti o ní ipa jùlọ ti ilẹ̀ Áfíríkà (MIPAD).

Ibẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Onos ni ìpínlẹ̀ Delta ni Gúúsù Nàìjíríà níbi tí ó ti gba ẹ̀kọ̀ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ áti gírámà lẹ́yìn ìgbà tí ó gba ìdàsílẹ̀ si Delta State University, Abraka níbi tí ó ti parí ẹ̀kọ́ gíga àkọ́kọ́ ni èdè Faranse. Onos ti bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ rẹ̀ láti ìgbà tí o ti wà ni ilé ẹ̀kọ́ alakọbẹrẹ, [1] tí o šì jẹ́ akópa lára àwọn tí wọ́n wà ní onírúurú ẹgbẹ́ akọrin àti àwọn ẹgbẹ ṣáájú ki o to lọ si ìlú Èkó ni ọdún 2004 níbi tí o ti bẹ̀rẹ̀ gbígbà sílẹ̀ orin àkọ́kọ́ rẹ, “Ijó” ti FLO ṣe jáde. .

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named worship1