Ori

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orí ènìyàn
Orí ènìyàn

Orí gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yà ara jẹ́ ẹ̀yà ara tí ó dúró lé ọrùn. Nínú orí ni a ti rí [[ojú]], imú, ẹnu àti etí.

Orí gẹ́gẹ́ bí ipò jẹ́ olùdarí (leader) ẹgbẹ́ kan tàbí ọ̀gbà kan.

Orí sì tún lè túmọ̀ sí ìpín tàbí kádàrá ẹni. Orúkọ mìíràn fún orí tí ó dúró fún kádàrá ni àyànmọ́ tàbí orí inú


Ìwé ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adekunle, B. O. (2012). Orí Bíbọ Láwùjọ Yorùbá. B. A project submitted to the Department of Linguistics African and Asian Studies, University of Lagos.