Jump to content

Orin Ọdún Yìí A Tura

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọdún Yìí A Tura jẹ́ orin àwọn Ẹlẹ́sìn ọmọ lẹ́yìn Jésù tí gbajúgbajà akọrin ìgbàgbọ́, Ajíyìnrere àti olùdarí ẹgbẹ́ Obìnrin Rere tí ìjọ C.A.C. tí ìlú Ìbàdàn, Dèbórà Adébọ́lá Fáṣọyin kọ fún ìgbà pípẹ́, ṣùgbọ́n tí àwo rẹ̀ jáde lọ́dún 2012. [1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Odun Yi Atura". Spotify. 2012-02-26. Retrieved 2020-01-01. 
  2. "Mrs. D. A. Fasoyin lyrics". musiXmatch. 2014-01-24. Retrieved 2020-01-01.