Jump to content

Orlando Julius

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orlando Julius
Julius playing in Montreal in 2016
Julius playing in Montreal in 2016
Background information
Orúkọ àbísọOrlando Julius Aremu Olusanya Ekemode
Ọjọ́ìbí(1943-09-22)22 Oṣù Kẹ̀sán 1943
Ikole, Nigeria
Aláìsí14 April 2022(2022-04-14) (ọmọ ọdún 78)
Irú orinAfrobeat,[1] Afro-soul, highlife[2]
Occupation(s)Musician
InstrumentsSaxophone, drums
Years active1960s–2022

Orlando Julius Aremu Olusanya Ekemode, tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Orlando Julius tàbí Orlando Julius Ekemode (tí wọ́n bí ní 22 September 1943 tó sì ṣaláìsí ní14 April 2022)[3] jẹ́ olórin, afunfèrè, olórí-ẹgbẹ́-orin, àti akọrinkalẹ̀, tó ṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú afrobeat music.[3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :2
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :4
  3. 3.0 3.1 Denselow, Robin (26 April 2022). "Orlando Julius obituary". The Guardian. Archived from the original on 27 April 2022. Retrieved 27 April 2022.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)