Jump to content

Ouagadougou Cathedral

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Cathedral Ouagadougou

Ouagadougou Cathedral (Faransé: Cathédrale de l'Immaculée-Conception de Ouagadougou) jẹ́ cathedral ti ìjọ Roman Catholic Archdiocese ti OuagadougouOuagadougou, olú ìlú Burkina Faso. Apostolic vicar Joanny Thévenoud ni ó kọ́ ìjọ náà láàrin àwọn ọdún 1930s, nígbà tí àríwá Áfríkà sì wà lábẹ́ ìdarí orílẹ̀ èdè France,[1] wọ́n sí ilé ìjọsìn náà ní ọjọ́ kàndínlógún oṣù kínní ọdún 1936,[2] lẹ́yìn tí wọ́n fi ọdún méjì kọ.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "90 ans de l'ordination épiscopale de Mgr Joanny Thévenoud" (in French). Peres-blancs.cef.fr. Archived from the original on 5 March 2017. Retrieved 10 September 2016. 
  2. Rupley, Lawrence; Bangali, Lamissa; Diamitani, Boureima (7 February 2013). Historical Dictionary of Burkina Faso. Scarecrow Press. p. 39. ISBN 978-0-8108-8010-8. https://books.google.com/books?id=PzXEKPYNXm8C&pg=PR39.