Owen Chamberlain

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Owen Chamberlain

Owen Chamberlain jẹ́ ọmọ bíbí ìlú San Francisco, ní orílẹ̀ èdè California, Chamberian kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Germantown Friends School ní orílẹ̀ èdè Philadelphia ní ọdún 1937. Ó kọ́ ìmọ̀ ẹ̀kọ́ physics ní Dartmouth College, níbi tó ti jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Alpha Theta ti ẹ̀ka Theta Chi àti ní University of California Berkeley. Ó wà ní ilé ìwé náà títí di ìgbà tí ogun àgbáyé kejì bẹ̀rẹ̀, lásìkò ìgbà náà ní o darapọ̀ mọ tí ó sì kópa nínu Manhattan Project ní ọdún 1942, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Segrè ní Berkeley àti ní Los_Alamos, _New_Mexico. Owen fẹ́ arábìnrin kan tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Beatrice Babette Copper ní ọdún 1943 tí ó sì bí ọmọ mẹ́rin fún.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]