Paramaribo
Ìrísí
Paramaribo | |
---|---|
The street Waterkant in Paramaribo | |
Nickname(s): Par'bo | |
Country | Suriname |
District | Paramaribo District |
Population | |
• Estimate ({{{pop_est_as_of}}}) | 242,946 |
Time zone | UTC-3 (ART) |
Paramaribo (àlàjẹ́: Par′bo) ni olú-ìlú àti ìlú tí ó tobí jùlọ ní orílẹ̀-èdè Suriname. Eti bebe odo Suriname ni agbegbe Paramaribo yi wa. Eniyan ti o to oji-le-nigba o le eyokan ni eto ikaniyan orile-ede Suriname ni odun 2012 se akosile re wipe o ngbe ni agbegbe Paramaribo. Ni apa ariwa-ila-oorun gusu Amerika ni agbegbe Paramaribo ti wa ri.
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]External links
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |