Argẹntínà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Argentina)
Jump to navigation Jump to search
Argentine Republic[1]
República Argentina
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
MottoEn unión y libertad
"In Unity and Freedom"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèHimno Nacional Argentino
Orthographic projection of Argentina
Orthographic projection of Argentina
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Buenos Aires
34°36′S 58°23′W / 34.6°S 58.383°W / -34.6; -58.383
Èdè àlòṣiṣẹ́ Spanish
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  86.4% European (mostly Italian and Spanish)
8% Mestizo
4% Arab and East Asian
1.6% Amerindian
[2][3]
Orúkọ aráàlú Ará Argẹntínà
Ìjọba Federal presidential republic
 -  President Alberto Fernández
 -  Vice President Cristina Fernández de Kirchner
 -  Supreme Court President Carlos Rosenkrantz
Independence from Spain 
 -  May Revolution 25 May 1810 
 -  Declared 9 July 1816 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 2,766,890 km2 (8th)
1,068,302 sq mi 
 -  Omi (%) 1.1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2008 40,482,000 (33rd)
 -  2001 census 36,260,130 
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $572.668 billion[4] (23rd)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $14,408[4] (57th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $324.767 billion[4] (31st)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $8,171[4] (66th)
Gini (2006) 49[5] (high
HDI (2006) 0.860 (high) (46th)
Owóníná Peso (ARS)
Àkókò ilẹ̀àmùrè ART (UTC-3)
 -  Summer (DST) ART (UTC-2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right (trains ride on the left)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ar
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +54
Salta

Argẹntínà Nínú ètò ìkànìyàn 1995, iye àwọn ènìyàn tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Ajẹntínà (Argentiana) lé díẹ̀ ní mílíọ̀nù mẹ́rìnlélógójì àti àti ààbọ̀ (34, 513, 000). Èdè Pànyán-àn ni èdè tí wọ́n fi ń ṣe ìjọba ní ibẹ̀. Àwọn èdè mìíràn tí wọ́n tún ń sọ ní orílè-èdè yìí lé ní ogún. Lára àwọn ogún èdè yìí ni àwọn èdẹ̀ tí wọ́n ń pè ní Àmẹ́rídíánà (Ameridian Languages) wà. Ara àwọn èdè. Àmérídíánà yìí ni ‘Guarani, Araucanian, Metaco àti Quechua’. Àwọn èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwọn tí ó wá se àtìpó ń sọ. Lára wọn ni èdè Ítílì (Ìtahàn) àti Jámánì (Herman). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ti ń gbilẹ̀ sí i ní orílẹ̀-èdè yìí gẹ́gẹ́ bí èdè fún òwò àgbáyé àti èdè àwọn tí ó ń ṣe àbẹ̀wò wá sí ibẹ̀ (International trade and tourism). Wọ́n ń lo èdè Gẹ̀ẹ́sì yìí pẹ̀lú èdè Pànyán-àn.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Article 35 of the "Constitution" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2007-11-22.  gives equal recognition to "United Provinces of the River Plate", "Argentine Republic" and "Argentine Confederation" and authorises the use of "Argentine Nation" in the making and enactment of laws
  2. Ben Cahoon. "Argentina". World Statesmen.org. 
  3. "Encuesta Complementaria de Pueblos Indígenas 2004-2005". National Institute of Statistics and Census of Argentina.  (Híspánì)
  4. 4.0 4.1 4.2 4.3 "Argentina". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  5. "Distribution of family income – Gini index". The World Factbook. CIA. Retrieved 2009-09-01.