Argẹntínà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Argentine Republic[1]
República Argentina
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
MottoEn unión y libertad
"In Unity and Freedom"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèHimno Nacional Argentino
Orthographic projection of Argentina
Orthographic projection of Argentina
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Buenos Aires
34°36′S 58°23′W / 34.6°S 58.383°W / -34.6; -58.383
Èdè oníbiṣẹ́ Spanish
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  86.4% European (mostly Italian and Spanish)
8% Mestizo
4% Arab and East Asian
1.6% Amerindian
[2][3]
Orúkọ aráàlú Ará Argẹntínà
Ìjọba Federal presidential republic
 -  President Cristina Fernández de Kirchner
 -  Vice President Julio Cobos
 -  Supreme Court President Ricardo Lorenzetti
Independence from Spain 
 -  May Revolution 25 May 1810 
 -  Declared 9 July 1816 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 2,766,890 km2 (8th)
1,068,302 sq mi 
 -  Omi (%) 1.1
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2008 40,482,000 (33rd)
 -  2001 census 36,260,130 
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $572.668 billion[4] (23rd)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $14,408[4] (57th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $324.767 billion[4] (31st)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $8,171[4] (66th)
Gini (2006) 49[5] (high
HDI (2006) 0.860 (high) (46th)
Owóníná Peso (ARS)
Àkókò ilẹ̀àmùrè ART (UTC-3)
 -  Summer (DST) ART (UTC-2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right (trains ride on the left)
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ar
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +54
Salta

Argentina Nínú ètò ìkànìyàn 1995, iye àwon ènìyàn tí ó wà ní orílè-èdè Ajentínà (Argentiana) lé díè ní mílíònù mérìnlélógójì àti àti ààbò (34, 513, 000). Èdè Pànyán-àn ni èdè tí wón fi ń se ìjoba ní ibè. Àwon èdè mìíràn tí wón tún ń so ní orílè-èdè yìí lé ní ogún. Lára àwon ogún èdè yìí ni àwon èdè tí wón ń pè ní Àmérídíánà (Ameridian Languages) wà. Ara àwon èdè. Àmérídíánà yìí ni ‘Guarani, Araucanian, Metaco àti Quechua’. Àwon èdè tí ó tún wà lára ogún yìí ni èdè tí àwon tí ó wá se àtìpó ń so. Lára won ni èdè Ítílì (Ìtahàn) àti Jámánì (herman). Èdè Gèésì ti ń gbilè sí i ní orílè-èdè yìí gégé bí èdè fún òwò àgbáyé àti èdè àwon tí ó ń se àbèwò wá sí ibè (International trade and tourism). Wón ń lo èdè Gèésì yìí pèlú èdè Pànyán-àn.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]