Jump to content

Paschaline Alex Okoli

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Paschaline Alex Okoli
Ọjọ́ìbíNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaImo State University
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2010–present

Paschaline Alex Okoli jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ Cordelia nínu eré aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jenifa's Diary .

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Paschaline wá láti agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Orumba south local government ní Ìpínlẹ̀ Anámbra. Ó gba oyè-ẹ̀kọ́ nínu ìmọ̀ èdè Faransé láti ilé-ẹ̀kọ́ gíga Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Ímò.[1]

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2010 pẹ̀lú kíkópa nínu fíìmù tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Definition Of Love.[2] Ṣùgbọ́n ó di ìlúmọ̀ọ́ká nígbà tí ó kópa gẹ́gẹ́ bi Cordelia nínu eré aláwàdà kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jenifa's Diary,[3][4] èyí tí ó ṣe pẹ̀lú Fúnkẹ́ Akíndélé.

Àwọn ìyẹ́sí rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n yaan Paschaline fún àmì-ẹ̀yẹ City People Movie Award kan ní ẹ̀ka ti ojú tuntun òṣèré tí ó dára jùlọ nínu ọdún (eré èdè Gẹ̀ẹ́sì).

Awuye tí ó wà lóri rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Paschaline ti sọ nígbà kan rí pé òun le kó ipa oníhòhò tí wọ́n bá le san owó tí ó tówó fún òun.[5][6][7][8] Paschaline maá n gbé àwọn fọ́tò ara rẹ̀ tí kò fẹ́ẹ̀ bójúmu sí orí ayélujára ní gbogbo ìgbà.[9][10]


Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Actress Paschaline Alex Okoli celebrates her birthday with raunchy photos.". www.naijaloving.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-01. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. mybiohub. "Paschaline Alex Okoli Biography | MyBioHub". www.mybiohub.com. Retrieved 2017-12-01. 
  3. "I can act nude – Cordelia of Jenifa’s Diary | National Pilot Newspaper". thenationalpilot.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-01. 
  4. "Complete List of Jenifa's Diary Cast Full Names, Profile & Celebrities Featured - Jenifa's Diary Full Series Download Links, Casts and Spoilers.". thejenifasdiary.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-09-06. Retrieved 2017-12-01. 
  5. ""I Can Go Nude For A Movie"- Actress Paschaline Alex Okoli (Video)" (in en-US). GistReel. 2017-09-04. https://www.gistreel.ng/i-c/. 
  6. "[E!News Paschaline Alex Okoli: I Can Go Nude For A Movie Depending On The Amount"] (in en-US). IJEBULOADED. 2017-09-04. https://ijebuloaded.com/enews-paschaline-alex-okoli-can-go-nude-movie-depending-amount/. 
  7. ""I can go nude for a movie" — Actress Paschaline Alex Okoli - NAIJAXTREME" (in en-US). NAIJAXTREME. 2017-09-04. https://naijaxtreme.com/can-go-nude-movie-actress-paschaline-alex-okoli/. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  8. "Actress Paschaline Alex Okoli Talks Acting Nude Scenes" (in en-US). Realchannel65. 2017-09-05. Archived from the original on 2019-03-06. https://web.archive.org/web/20190306043509/https://realchannel65.ng/paschaline-alex-okoli/. 
  9. "Actress Paschaline Alex Okoli Slays In Daring Birthday Photos" (in en-gb). Nigeriafilms.com. https://www.nigeriafilms.com/celebrity-gossips/139-celebrities-birthday/31858-actress-paschaline-alex-okoli-slays-in-daring-birthday-photos. 
  10. "Actress Paschaline Okoli Poses in Hots Short Nightgown to Celebrate Her Birthday (PHOTOS) - Gistmania". http://www.gistmania.com/talk/topic,268053.0.html. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]