Patricia Etteh.
Patricia Olubunmi Foluke Etteh | |
---|---|
Speaker of the House of Representatives of Nigeria | |
In office 6 June 2007 – 30 October 2007 | |
Deputy | Babangida Nguroje |
Asíwájú | Aminu Bello Masari |
Arọ́pò | Dimeji Bankole |
Aṣojú ìkọ̀ Ayedaade/Isokan/Irewole | |
In office 1999–2007 | |
Constituency | Ayedaade/Isokan/Irewole |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹjọ 1953 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | AD, lẹyìn náà PDP |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Married |
Àwọn ọmọ | Two |
Residence | Isale Popo, Ikire |
Alma mater | University of Buckingham |
Profession | Onídìrí, agbejọ́rò àti olóṣèlú |
Patricia Olubunmi Foluke Etteh (tí a bí ní ọjọ́ Kẹtàdínlọ́gún oṣù kẹjọ 1953)[1] jé omo egbe ile igbimo asojú Naijiria fún ekun Ayedaade/isokan/irewole lati osu kefa odún 1999 titi di osu kewaa odun 2007. Ó jé omo egbe Alliance for Democracy(AD) kí o tó padà darapo egbé People's Democratic Party(PDP).[2]
Àárò ayé àti èkó rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bi Etteh ni 17 August 1953. O kose onidiri sugbon o pada tèsíwájú ninú èkó rè láti kékó Ofin ní yunifásitì ti Buckingham ni United Kingdom ní odun 2013, ósì padà wá sí Nàìjíríà fún ipe sisé ofin ní odun 2016. [3]
Òsèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Etteh un se asojú Ayedaade/Isokan/Irewole constituency ni ìpínlè Osun. O kókó wolé lábé egbe oselu Alliance for Democracy(AD) sùgbón o yí si egbe oselu People's Democratic Party(PDP) nígbà to fé lo sáà keji ní ipo. Ni odun 2007, a dibo yan sí ipò adari(speaker) ilé ìgbìmò asofin, oun ni obinrin akoko to kókó di irú ipò béè mú nínú isejoba Nàìjíríà.[4] Óun àti ígbákejì rè padà kowe fi ipò náà sílè léyìn tí afi èsùn jibiti kan wón.[2]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "NIGERIAN TRIBUNE - News". tribune.com.ng. 2007-09-26. Archived from the original on 2007-09-26. Retrieved 2022-05-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 2.0 2.1 "Patricia Etteh,Role Model,Hairdresser,Beauty Therapist and Politician, Speaker of the Nigerian House of Representatives and Entreprenuer, Prominent Nigerian, Nigeria Personality Profiles". Nigeriagalleria. 1953-08-17. Retrieved 2022-05-22. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "Nigeriagalleria 1953" defined multiple times with different content - ↑ "Former House of Reps Speaker, Patricia Etteh, among 4,225 new lawyers". Vanguard News. 2016-11-29. Retrieved 2022-05-22.
- ↑ "News -- Mark, Etteh, emerge Senate President, Speaker". odili.net. 2007-10-25. Archived from the original on 2007-10-25. Retrieved 2022-05-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)<nowiki>